Abubakar Tafawa Balewa

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Tafawa Balewa)

Abubakar Tafawa Balewa (December 1912 – January 15, 1966) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè e Nàìjíríà, láti apá àríwá ilẹ̀ Nàìjíríà[1]. Balewa jẹ́ Alákòóso Agba (prime minister) àkọ́kọ́ fún ilẹ̀ Nàìjíríà ní ìgbà òṣèlú àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà lẹ́yìn ìgbà tí Nàìjíríà gba òmìnira ní ọdún-un 1960.[2] Ẹni àyẹ́sí ni kárí ayé, ó gba ọ̀wọ̀ ní orílẹ̀ Áfíríkà gẹ́gẹ́ bí ìkan lára àwọn n tí wọ́n dábàá dídá sílẹ̀ àkójọpọ̀ ẹgbẹ́ ìsọ̀kan ti Afrika (Organization of African Unity, OAU)[3].[4][5]

Abubakar Tafawa Balewa
Alakoso Agba ile Nàìjíríà
In office
October 1, 1959 – January 15, 1966
Arọ́pòNone
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1912
Bauchi, Nàìjíríà
Aláìsí15 January, 1966
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNorthern People's Congress

Ìgbà èwe àti iṣẹ́ ọwọ̀

àtúnṣe


  1. Faal, Courtney; Faal, Courtney (2009-05-09). "Sir Abubakar Tafawa Balewa (1912-1966) •". Welcome to Blackpast •. Retrieved 2023-06-20. 
  2. "Sir Abubakar Tafawa Balewa". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2023-06-12. 
  3. "Abubakar Tafawa Balewa". New World Encyclopedia. 1959-10-01. Retrieved 2023-06-20. 
  4. Nigeria, Guardian (2022-01-12). "Remembering Abubakar Tafawa Balewa, 56 years later". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2023-06-12. 
  5. "Sir Abubakar Tafawa Balewa". Encyclopedia.com. 2023-05-25. Retrieved 2023-06-12.