Taherah Rahman
Tahera Shireen Rahman tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, oṣù kínní ọdún 1991. Ó jẹ́ ọmọ Améríkà àti oníròyìn tí ó gbajúmọ̀ fún jíjẹ́ àkọ́kọ́ oníròyìn obìrin tí ń wọ ìjáábù ní Amẹ́ríkà ní oṣù kejì ọdún 2018, fún ilé iṣẹ́ amóunmáwòrán WHBF lẹ́yìn tí ó ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Olùdarí ètò ní ilé-iṣẹ́ ọ̀ún tẹ́lẹ̀[3][4][5][6][7][8][9][10][11][12][13][14][15]
Tahera Rahman | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kínní 1991[1] Chicago, Illinois, U.S.[2] |
Iṣẹ́ | News producer Newscaster |
Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹkọ́ rẹ
àtúnṣeTaherah Rahman wá láti ìdílé àwọn àrìnrìnàjò láti Pakistan àti India ní ẹ̀yìn odi Chicago..[8] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Loyola ní Chicago níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí Bachelor of Arts nínú ẹ̀kọ́ ìròyìn kíkọ àti ẹ̀kọ́ ìbáṣepọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé.Rahman ni ó tún jẹ́ àkọ́kọ́ mùsùlùmí tí ó dipò ọ̀gá àgbà tí ń àtúnyẹwò ìròyìn ti ìwé ìròyìn ti àwọn akẹ́ẹ́kọ́ tí ń jáde ní ọ̀sẹ̀ẹ̀sẹ̀ ní Loyola.[16]
Iṣẹ́
àtúnṣeTaheerah Rahman kọ́ jẹ́ Olùdarí ètò àti olóòtú ní Rédíò ìsìláàmù ojóojúmọ́ (daily Radio Islam show) ní WCEV 1450 AM ní Chicago tí ó jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ Àjọ Sound Vision láti ọdún 1999 di 2019.[17] Taherah ṣiṣẹ́ fún ilé-iṣẹ́ amóunmáwòrán WHBF títí di oṣù kẹsàn-án ọdún 2019. Nísìnyí, ó ń ṣiṣẹ́ fún ilé-iṣẹ́ amóunmáwòrán KXAN ní Austin, Texas.[18]
Àwọn atọ́ka
àtúnṣe- ↑ Rahman, Tahera (2019-01-24). "Tahera Rahman on Twitter". Twitter (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-14. Retrieved 2019-10-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Tahera Rahman". WHBF - OurQuadCities.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-02-07. Archived from the original on 2019-10-14. Retrieved 2019-10-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Ikomoni, Alexandria (2019-09-27). "Bittersweet moment! You all will be missed at the station! So excited for your future and journey.pic.twitter.com/JOvxf2sDOX". @AIkomoniTV (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-14.
- ↑ "Meet the first American TV reporter to wear a hijab on the air" (in en-US). TODAY.com. https://www.today.com/style/tahera-rahman-first-air-tv-reporter-wear-hijab-t124701.
- ↑ Lundberg, Tiffany (2018-02-10). "Tahera's Journey: Making history and breaking barriers" (in en-US). OURQUADCITIES. Archived from the original on 2019-05-01. https://web.archive.org/web/20190501023730/https://www.ourquadcities.com/news/taheras-journey-making-history-and-breaking-barriers/963693768.
- ↑ "America just got its first Muslim TV reporter who wears a hijab" (in en-GB). Metro. 2018-02-27. https://metro.co.uk/2018/02/27/america-just-got-its-first-full-time-muslim-tv-reporter-who-wears-a-hijab-7344956/.
- ↑ "'My America, too.' This Iowa TV reporter is the first to wear a hijab on air in the U.S. — haters or no haters" (in en). Des Moines Register. https://www.desmoinesregister.com/story/life/2018/02/23/iowa-journalist-makes-history-first-hijabi-reporter-american-tv-tahera-rahman-whbf-local-4/335297002/.
- ↑ 8.0 8.1 Farabaugh, Kane. "Hijab-Wearing TV Reporter Charts New Path for Muslim-Americans" (in en). VOA. https://www.voanews.com/a/muslim-american-reporter/4285574.html.
- ↑ "Tahera Rahman Becomes First Full-Time TV Reporter to Wear Hijab" (in en). The Hollywood Reporter. https://www.hollywoodreporter.com/news/tahera-rahman-becomes-first-full-time-tv-reporter-wear-hijab-air-1084355.
- ↑ Herald Staff Report (2018-09-13). "Panel will focus on racism" (in en). Clinton Herald. http://www.clintonherald.com/news/local_news/panel-will-focus-on-racism/article_fc5163fc-19af-555c-9ed0-94e6af3b3c5b.html. "The panel discussion will feature WHBF news reporter, Tahera Rahman, the first woman in hijab to work as an on-air reporter for American television. Tahera joined the WHBF Local 4 News team as a producer in May 2016."
- ↑ Jones, Ja'han (2018-03-05). "Tahera Rahman Just Became The First Full-Time Hijabi Reporter On Air In America" (in en-US). Huffington Post. https://www.huffingtonpost.com/entry/tahera-rahman-is-making-american-history-in-her-hijab_us_5a99cd84e4b089ec353a43a5.
- ↑ Hancock, Amanda. "Rock Island TV reporter Tahera Rahman featured on NBC's 'Today' show" (in en). The Quad-City Times. https://qctimes.com/news/local/rock-island-tv-reporter-tahera-rahman-featured-on-nbc-s/article_cb2001d3-64d9-54fd-80fb-aebf99205c60.html.
- ↑ "Meet the USA's first hijabi newsreader" (in en-US). Emirates Woman. 2018-02-19. http://emirateswoman.com/tahera-rahman-is-the-usas-first-hijabi-newsreader/.
- ↑ "America's 1st Hijab-Wearing TV Reporter Tahera Rahman Goes on Air Without Glitch" (in en). Al Bawaba. 2018-08-09. https://www.albawaba.com/editorchoice/americas-1st-hijab-wearing-tv-reporter-tahera-rahman-goes-air-without-glitch-1171370.
- ↑ "First full-time hijab-wearing on-air reporter breaks barriers in US" (in en-US). The Times of Israel. https://www.timesofisrael.com/first-full-time-hijab-wearing-on-air-reporter-breaks-barriers-in-us/.
- ↑ "Tahera Rahman". WHBF - OurQuadCities.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-02-07. Archived from the original on 2019-10-14. Retrieved 2021-07-13.
- ↑ Crowder, Courtney (2018-02-22). "'My America, too.' This Iowa TV reporter is the first to wear a hijab on air in the U.S. — haters or no haters". The Des Moines Register. https://www.desmoinesregister.com/story/life/2018/02/23/iowa-journalist-makes-history-first-hijabi-reporter-american-tv-tahera-rahman-whbf-local-4/335297002/.
- ↑ "Tahera Rahman". KXAN Austin (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-24. Archived from the original on 2021-07-13. Retrieved 2021-07-13.