Taiwo Olayemi Elufioye jẹ́ onímọ̀ ògùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó si ṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ pẹ̀lú ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Ibadan. Ó jẹ́ ìkan láàrin àwọn onímọ̀ ni ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of the SciencesPhiladelphia.[1]

Taiwo Olayemi Elufioye
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Ilé-ẹ̀kọ́University of Ibadan
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síElsevier Foundation Awards for Early Career Women Scientists in the Developing World

Ó gbà owó ńlá láti ọ̀dọ̀ MacArthur Foundation láti lè ṣe oríṣiríṣi àyẹ̀wò lórí àwọn òun ọ̀gbìn tí ó wà ní Nàìjíríà tí ó lè ṣe ìwòsàn fún àwọn àrùn.[2][3][4] Ní ọdún 2014, òun pẹ̀lú àwọn obìnrin mẹ́rin jọ gba àmì ẹ̀yẹ Early Career Women Scientist in the Developing World láti ọ̀dọ̀ Elsevier Foundation Awards.[5][6]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Elufioye gba owó lọ́wọ́ MacArthur Foundation láti ṣiṣẹ́ ìwádìí lórí oríṣiríṣi egbò-igi orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti lè ṣàyẹ̀wò àrùn kan, àti láti wá ojútùú si.[7]

NÍ ọdún 2014, Elufioye jẹ́ ọ̀kan lára àwọn obìnrin tí wọ́n gba àmì-ẹ̀yẹ ti Elsevier Foundation Awards for Early Career Women Scientists in the Developing World.[8] Elufioye gba àmì-ẹ̀yẹ fún iṣẹ́ rẹ̀ lórí iṣẹ́ ìwòsàn àwọn egbò-igi ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[9] Iṣẹ́ ìwádìí rẹ̀ dálé lórí àwọn ohun tí wọ́n le fi ṣe ìwòsàn fún àìsàn màléríà, egbò, oyèrírá, ẹ̀tẹ̀ àti àrùn jẹjẹrẹ.[10] Àmì-ẹ̀yẹ ti Elsevier Foundation ni wọ́n fún Yaiwo ní ayẹyẹ American Association for the Advancement of Science (AAAS), lásìkò ìpàdé ọdọọdún wọn ní Chicago, ó sì tún gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbùn àti $5000.[11] Nígbà tó gba àmì-ẹ̀yẹ náà, igbákejì Ààrẹ ti Yunifásítì ìlú Ìbàdàn, Isaac Adewole, sọ pé àṣeyọrí Elufioye máa jẹ́ ìwúrí fún àwọn obìnrin mìíràn nínú iṣẹ́ sáyẹ́ǹsì, àti pé ó jẹ́ ẹni ẹ̀yẹ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn ní ilẹ̀ adúláwọ̀ lápaapọ̀.[12]

Wọ́n ti ṣàtẹ̀jáde Elufioye ní African Journal of Biomedical Research,[13] Pharmacognosy Research,[14] the International Journal of Pharmaceutics,[15] àti African Journal of Traditional, Complementary and Alternative Medicines.[16]

Awọ̀n ìtókàsi

àtúnṣe
  1. "USciences Hosts Fulbright Scholar Studying Drugs to Treat Neurodegenerative Diseases". University of the Sciences (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-12-02. Retrieved 2020-06-02. 
  2. "Taiwo Elufioye, UI Chemist Celebrated in U.S.". Nigerian Tribune. 11 October 2014. http://www.tribune.com.ng/achievers/item/18247-taiwo-elufioye-ui-chemist-celebrated-in-us-receives-prize-for-women-in-science. 
  3. "Nigerian woman, Elufioye, wins 2014 scientists award". Blueprint. 10 March 2014. Archived from the original on 17 September 2016. https://web.archive.org/web/20160917092441/http://www.blueprint.ng/2014/03/10/nigerian-woman-elufioye-wins-2014-scientists-award/. 
  4. "UI Scientist, Dr. Taiwo Olayemi-Elufioye Wins Women Global Award". Naijalog. http://naijalog.com/ui-scientist-dr-taiwo-olayemi-elufioye-wins-women-global-award/. 
  5. "The Elsevier Foundation honors Early Career Women Scientists from Developing Countries for Research into the Medicinal Properties of Natural Compounds". The Elsevier Foundation. 12 February 2014. Retrieved 1 February 2016. 
  6. Obayendo, Temitope (11 March 2014). "UI Pharmacognosy Lecturer, Wins Women Global Award". Pharmanews. http://www.pharmanewsonline.com/ui-pharmacognosy-lecturer-wins-women-global-award/. 
  7. "Doctoral Grantees (Taiwo Olayemi Elufioye)". MacArthur Grants Awardees. University of Ibadan. Archived from the original on 3 March 2015. Retrieved 2 February 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "The Elsevier Foundation honors Early Career Women Scientists from Developing Countries for Research into the Medicinal Properties of Natural Compounds". The Elsevier Foundation. 12 February 2014. Retrieved 1 February 2016. 
  9. Obayendo, Temitope (11 March 2014). "UI Pharmacognosy Lecturer, Wins Women Global Award". Pharmanews. http://www.pharmanewsonline.com/ui-pharmacognosy-lecturer-wins-women-global-award/. 
  10. "Nigerian woman, Elufioye, wins 2014 scientists award". Blueprint. 10 March 2014. Archived from the original on 17 September 2016. https://web.archive.org/web/20160917092441/http://www.blueprint.ng/2014/03/10/nigerian-woman-elufioye-wins-2014-scientists-award/. 
  11. "Taiwo Elufioye, UI Chemist Celebrated in U.S.". Nigerian Tribune. 11 October 2014. http://www.tribune.com.ng/achievers/item/18247-taiwo-elufioye-ui-chemist-celebrated-in-us-receives-prize-for-women-in-science. 
  12. "UI Scientist, Dr. Taiwo Olayemi-Elufioye Wins Women Global Award". Naijalog. http://naijalog.com/ui-scientist-dr-taiwo-olayemi-elufioye-wins-women-global-award/. 
  13. Elufioye, Taiwo Olayemi; Alafe, Atinuke Omoyeni; Faborode, Oluwaseun Samuel; Moody, Olanrewaju Jones (2014). "Anti-Inflammatory and Analgesic Activity of Secridaca Longepedunculata Fers (Polygalaceae) Leaf and Stem Bark Methanolic Extract". African Journal of Biomedical Research 17 (3): 187–191. http://www.ajbrui.net/ojs/index.php/ajbr/article/view/377. Retrieved 1 February 2016. 
  14. Onasanwo, Samuel Adetunji; Emikpe, Benjamin Obukowho; Elufioye, Taiwo Olayemi; Ajah, Austin Azubuike (2013-07-01). "Anti-ulcer and ulcer healing potentials of Musa sapientum peel extract in the laboratory rodents" (in en). Pharmacognosy Research 5 (3): 173–178. doi:10.4103/0974-8490.112423. PMC 3719258. PMID 23900937. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3719258. 
  15. Mojisola, Cyril-Olutayo Christiana (2012). "Ethnobotanical Survey of Plants Used as Memory Enhancer and Antiaging in Ondo State, Nigeria". International Journal of Pharmaceutics. http://kevaind.org/download/herbs%20useful%20in%20memory.pdf. 
  16. Olayemi, E. T.; Arabela, A. O. (2015-01-01). "Quality evaluation of Poza bitters, a new poly herbal formulation in the Nigerian market". African Journal of Traditional, Complementary and Alternative Medicines 12 (1): 17–22. doi:10.4314/ajtcam.v12i1.3. ISSN 0189-6016. http://www.ajol.info/index.php/ajtcam/article/view/115450.