Olóyè Daniel Conrad Taiwo (tí a bí ní ọdún 1781 tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ ogún oṣù kejì ọdún 1901), àwọn ènìyàn tún mọ̀ọ́ sí Taiwo Olówó[1]. Ó jẹ́ olùtà ohun ìjà ogun, olówó àwọn ẹrú, afifúni àti olórí àdúgbò kan nígbà tí Èkó wà lábé ìjọba Britain.

Taiwo Olowo
Ọjọ́ìbíDaniel Conrad Taiwo "Olowo"
1781
Isheri, Lagos
Aláìsí20 February 1901(1901-02-20) (ọmọ ọdún 119–120)
Lagos, Lagos Colony
Parent(s)
  • Chief Oluwole (father)

Ìpìlẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

A bí Taiwo Olowo ní ọdún 1781 ní Isheri, àdúgbò kan ní ìpínlẹ̀ Eko.[2] Baba rẹ̀, Oluwole, jẹ́ Olofin ìlú rẹ̀, ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1809.[3] Olowo kó lọ sí ìlú Èkó ní ọdún 1848 ó sì jẹ́ ẹrú Ogunmade fún ìgbà díẹ̀.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Olukoju, Akyeampong, Bates, Nunn, & Robertson (11 August 2014). Accumulation and Conspicuous Consumption: The Poverty of Entrepreneurship in Western Nigeria, ca. 1850–1930 in Africa's Development in Historical Perspective. Cambridge University Press, Aug 11, 2014. pp. 210–211. ISBN 9781139992695. 
  2. "Daniel Conrad Taiwo: 18th century Lagos Island business icon". National Mirror. Archived from the original on December 20, 2016. Retrieved 10 December 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Taiwo Conrad Olowo – Litcaf". 17 January 2016. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. Cole, Patrick (17 April 1975). Modern and Traditional Elites in the Politics of Lagos. Cambridge University Press, 1975. pp. 30–31. ISBN 9780521204392. https://archive.org/details/moderntraditiona0000cole/page/30.