Taiwo Olukemi Oluga je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Arábìnrin naa je ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà to n soju àgbègbè Ayedaade / Irewole / Isokan ti Ipinle Osun ni ile ìgbìmọ̀ asòfin agba kesan-an. [1] [2] [3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe