Tajudeen Adeyemi Adefisoye
Tajudeen Adeyemi Adefisoye Listen ⓘ (ojoibi 3 August 1984) je olóṣèlú omo orilẹ-ede Nàìjíríà, okùnrin onísòwò ati onínúrere. [1] Oun ni Oludasile ati Ààrẹ ile ise Small Alhaji Youth Foundation (SAYDEF), ajo ti o n sètò ìdàgbàsókè awọn odò nipinle Ondo, oun ni ọmọ egbe Social Democratic Party (SDP) to kere julo ati egbe oselu SDP ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin fun Idanre/Ifedore, Ondo State, Nigeria. [2] [3]
Tajudeen Adefisoye | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Tajudeen Adeyemi Adefisoye 3 Oṣù Kẹjọ 1984 Ondo State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Entrepreneur/Politician |
Ìrìnàjò òṣèlú
àtúnṣeTajudeen darapọ mo òṣèlú ni ọdun 2010. O ni erongba lati je ọmọ ile ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlè Ondo lábé ẹgbẹ́ òsèlú Labour Party lódun kàn náa sugbọn awọn alátakò ti won tu. Leyin naa lo kuro nínú ẹgbẹ́ Labour lo si egbe Action Congress of Nigeria (ACN) to ti di alaisi bayii nibi to ti ṣíṣe fun àwọn oludije gómìnà ACN ati awon oludije ile ìgbìmọ̀ asofin agba ni ọdún 2011 ati 2012. Lodun 2015, Tajudeen dije dupo ìdìbò alaabere ile ìgbìmọ̀ asofin ìpínlè Ondo labe agboorun ẹgbẹ́ òsèlú APC, ibo mejo lo si jawe olubori ninu idibo alaimoye nijoba ibile Idanre ni ipinlẹ Ondo. [4]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ http://www.signalng.com/meet-tajudeen-adeyemi-adefisoye-the-youngest-mhr-elect-in-southern-nigeria-%E2%80%A8/
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2019/04/i-will-not-support-rubber-stamp-speaker-small-alhaji/
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2021/08/rep-member-adefisoye-providing-leadership-at-37/
- ↑ http://www.signalng.com/meet-tajudeen-adeyemi-adefisoye-the-youngest-mhr-elect-in-southern-nigeria-%E2%80%A8/