Takeo Miki

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Japan

Takeo Miki tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1907, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹwàá ọdún 1988 jẹ́ Alákòóso Àgbà orílẹ̀-èdè Japan tẹ́lẹ̀. Òun ni Alákòóso Àgbà ókànlélógójì tí orílẹ̀ èdè Japan. Ó bẹ̀rẹ̀ ìṣèjọba rẹ̀ lọ́dún 1974 sí 1976. Ó gba ìjoba lọ́wọ́ Kakuei Tanaka gẹgẹ bíi Alákòóso Àgbà. Ìyàwó rẹ̀ ni Matusko Miki. Ó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní Meiji Unifásítì, Tokyo. Ó gbà ìwé-ẹ̀rí dókítà amòfin ní unifásitì`́ gúsù California, Los Angeles.[1]

Takeo Miki



Itokasi àtúnṣe

  1. Pace, Eric (1988-11-14). "Takeo Miki, Japanese Premier in 70's, Dies at 81". The New York Times. Retrieved 2019-04-25.