Coordinates: 61°30′N 023°46′E / 61.500°N 23.767°E / 61.500; 23.767

Tampere (sv: Tammerfors) jẹ ilu inu ilẹ ni Fínlándì. O wa ni ibuso 180 ni ariwa ti Helsinki, olu-ilu naa. O fẹrẹ to eniyan 250,000 ngbe ni Tampere.[1]

Tampere


  1. "Population in the urban and sparsely areas in term of age and gender, 2019" (in Èdè Finisi). Statistics Finland. 2019-12-31. Archived from the original on 2021-04-28. Retrieved 2021-06-10.