Àdàkọ:Use Nigerian English


Taoreed Lagbaja
Chief of Army Staff
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
19 June 2023
ÀàrẹBola Tinubu
AsíwájúFaruk Yahaya
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kejì 1968 (1968-02-28) (ọmọ ọdún 56)
Irepodun, Western State, Nigeria (now in Osun State)
Alma mater
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/service Nigerian Army
Years of service1987–present
Rank Major general

Ọ̀gágun Major General Taoreed Abíọ́dún Lágbájá (ni wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1968) jẹ́ Ọ̀gágun-àgbà tí ó gboyè Major General nínú iṣẹ́ ológun orílẹ̀ - èdè Nigeria. Òun ni Ọ̀gágun-àgbà yányán àwọn ológun Nigeria, Chief of Army Staff.[1][2][3] He was appointed on 19 June 2023 by President Bola Tinubu to succeed Lieutenant General Faruk Yahaya.

Ìgbà èwe rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Lágbájá ní ìlú Ìlobù ní ìjọba Ìbílẹ̀ Ìrẹ́pọ̀dùn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1968. Ó lo ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ ní ìlú Òṣogbo, níbi tí ó ti kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ní ilé-ìwé St Charles Grammar School and Local Authority Teachers College.[4]

Iṣẹ́ àtúnṣe

Wọ́n gbà á sí ilé-ìwé àwọn ológun Nigerian Defence Academy ọdún 1987. Wọ́n fún un lóye ológun (Second Lieutenant) lọ́jọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 1992 ẹgbẹ́ ológun Nigerian Infantry Corps.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Ogalla, Abubakar, Egbetokun, Lagbaja, Musa - Meet Nigeria new Service Chiefs". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-65954606. 
  2. Udeh, StellaO; Aguwa, EmmanuelN; Onwasigwe, ChikaN (2022). "Workplace burnout and psychological health of military personnel in a Nigerian barrack". Nigerian Journal of Medicine 31 (3): 302. doi:10.4103/njm.njm_31_22. ISSN 1115-2613. http://dx.doi.org/10.4103/njm.njm_31_22. 
  3. Ariemu, Ogaga (2023-06-20). "10 interesting things to know about new COAS, Maj Gen Lagbaja". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-20. 
  4. 4.0 4.1 Yusuf, Kabir (2023-06-20). "PROFILE: Major General Taoreed Lagbaja: New head of Nigerian Army". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-20.