Tatum O'Neal
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Tatum O'Neal jẹ olukọwe ati óṣere lobinrin ilẹ America ti a bini ọjọ karun óṣu November ni ọdun 1963[1].
Tatum O'Neal | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Tatum Beatrice O'Neal 5 Oṣù Kọkànlá 1963 Los Angeles, California, U.S. |
Iṣẹ́ | Actress, author |
Ìgbà iṣẹ́ | 1973–present |
Olólùfẹ́ | John McEnroe (m. 1986; div. 1994) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Parent(s) | Ryan O'Neal Joanna Moore |
Àwọn olùbátan | Griffin O'Neal (brother) Patrick O'Neal (sportscaster) |
Igbesi Ayè Arabinrin naa
àtúnṣeTatum ni wọn bisi Los Angeles, California fun óṣèrè Ryan O'Neal ati Joanna Moore. Awọn obi óṣere lobinrin naa pinya ni ọdun 1967[2][3]. Iya Tatum ku ni ọmọọdun mẹta lelọgọta lori arun jẹjẹrẹ ti lungs.Ni ọdun 2021, O'Neal kopa ninu filmu "Maṣè gbagbe" to dalori idani lẹ̀kọ ati iko ówó jọ lati ja fun aisan Alzheimer[4].
Filmography
àtúnṣeFilm
àtúnṣeọdun | Akọle | Ipa ti óṣèrè lobinrin naa ko | Akiyesi |
---|---|---|---|
1973 | Paper Moon | Addie Loggins | David di Donatello Award for Best Foreign Actress (tied with Barbra Streisand for The Way We Were) Golden Globe Award for New Star Of The Year – Actress Nominated – Golden Globe Award for Best Actress – Motion Picture Musical or Comedy |
1976 | The Bad News Bears | Amanda Wurlitzer | |
Nickelodeon | Alice Forsyte | ||
1978 | International Velvet | Sarah Brown | |
1980 | Circle of Two | Sarah Norton | |
Little Darlings | Ferris Whitney | ||
1982 | Prisoners | Christie | Unreleased |
1985 | Certain Fury | Scarlet | |
1992 | Little Noises | Stella | |
1996 | Basquiat | Cynthia Kruger | |
2002 | The Scoundrel's Wife | Camille Picou | San Diego Film Festival Award for Best Actress |
2003 | The Technical Writer | Slim | |
2006 | My Brother | Erica | |
2008 | Saving Grace B. Jones | Grace B. Jones | |
2010 | The Runaways | Marie Harmon | |
Last Will | Hayden Emery | ||
2012 | This Is 40 | Realtor | Cameo |
2013 | Mr. Sophistication | Kim Waters | |
2015 | Sweet Lorraine | Lorraine Bebee | |
She's Funny That Way | Waitress | Cameo | |
2017 | Rock Paper Dead | Dr. Evelyn Bauer | |
2018 | God's Not Dead: A Light in Darkness | Barbara Solomon | |
2019 | The Assent | Dr. Hawkins | |
2021 | Not to Forget | Doctor |
Television
àtúnṣeỌdun | Akọle | Ipa ti óṣere obinrin naa ko | Akiyesi |
---|---|---|---|
1984 | Faerie Tale Theatre | Goldilocks | Goldilocks and the Three Bears" |
1989 | CBS Schoolbreak Special | Kim | Episode: "15 and Getting Straight" |
1993 | Woman on the Run: The Lawrencia Bembenek Story | Laurie Bembenek | TV movie |
2003 | Sex and the City | Kyra | Episode: "A Woman's Right to Shoes" |
2004 | 8 Simple Rules | Ms. McKenna | Episode: "Opposites Attract: Part 3: Night of the Locust" |
Law & Order: Criminal Intent | Kelly Garnett | Semi-Detached" | |
2005 | Ultimate Film Fanatic | Judge | |
2005–2011 | Rescue Me | Maggie | Recurring role (Seasons 2–3, 5–7), Main role (Season 4); 39 episodes |
2006 | Dancing with the Stars | Herself | 5 episodes |
Wicked Wicked Games | Blythe Hunter | 51 episodes | |
2008 | Fab Five: The Texas Cheerleader Scandal | Lorene Tippit | TV movie |
2010 | RuPaul's Drag Race | Herself | Episode: "The Diva Awards" |
2011 | Ryan and Tatum: The O'Neals | Herself | |
2015 | Hell's Kitchen | Herself | Episode: "6 Chefs Compete" |
2017 | Criminal Minds | Miranda White | Episode: "Assistance Is Futile" |
2018 | Runaway Romance | Veronica Adson | TV movie |
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
àtúnṣeTatum jẹ ọdọ to kere julọ lati pegede ninu idije Ami ẹyẹ Akademi ni ọmọ ọdun mẹwa nibi ti ó ti ṣèrè gẹgẹbi Addie Loggins ninu èrè Paper Moon ni ọdun 1973[5]. Ni ọdun 1974,Tatum gba ami ẹyẹ Akademi gẹgẹbi oluranilọwọ óṣèrè lobinrin to dara ju[6].
Itokasi
àtúnṣe- ↑ http://www.filmreference.com/film/24/Tatum-O-Neal.html
- ↑ https://news.google.com/newspapers?id=_xMyAAAAIBAJ&pg=4717,1861129
- ↑ https://web.archive.org/web/20150425112536/http://www.biography.com/people/tatum-oneal-9542526
- ↑ https://filmdaily.co/obsessions/not-to-forget-movie/
- ↑ https://news.google.com/newspapers?id=LlU_AAAAIBAJ&pg=5803,3126219
- ↑ https://www.oscars.org/oscars/ceremonies/1974