Tawa Iṣhọla jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 23, óṣu December ni ọdun 1988. Arabinrin naa ṣere gẹgẹbi midfielder fun team awọn obinrin ti national lori bọọlu[1][2][3].

Tawa Iṣhọla
Personal information
Ọjọ́ ìbí23 Oṣù Kejìlá 1988 (1988-12-23) (ọmọ ọdún 35)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.54m
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2008Bayelsa Queens
2014–2015FC Minsk (women)37(23)
National team
2008Nigeria women's national football team0 (?)(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Elere naa kopa ninu olympic ọdun 2008 nibi ti o ti arabinrin naa ṣoju fun naigiria[4][5].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/tawa-ishola_prs436265/person.shtml
  2. https://www.allnigeriasoccer.com/read_news.php?nid=11992
  3. https://africanfootball.com/news/482120/Tawa-Ishola-leads-Nigeria-ladies-to-conquer-Belarus
  4. https://www.celebheightwiki.com/tawa-ishola-height
  5. https://www.playmakerstats.com/player.php?id=211283&epoca_id=0&search=1