Tawakel Karman
Tawakel Karman (Lárúbáwá: توكل كرمان Tawak[k]ul Karmān; Tawakul[1], Tawakkul[3]) je oloselu ara Yemen to je omo egbe Al-Islah[2] ati alakitiyan awon eto omoniyan to tun je olori egbe Women Journalists Without Chains to dasile ni 2005.[1]
Tawakel Karman | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | توكل كرمان |
Orílẹ̀-èdè | Yemeni |
Iṣẹ́ | Human rights activist,[1] journalist, politician[2] |
Political party | Al-Islah |
Àwọn ọmọ | Three |
Awards | 2011 Nobel Peace Prize |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |