Tayo Aderinokun
Olutayo Aderinokun (May 8, 1955 – June 14, 2011) jé omo orílé èdè Nàìjíríà onísòwò, ti o si tun je Oludari ile ifowopamo Guaranty Trust Bank titi di ojo ti o fi aye sile.[1][2]. O si je okan lara awon ti o ti gba ami eye idalola Member of the Federal Republic, okan lara ami eye ti ijoba orile ede Nàìjíríà ma n fi da awon eniyan jankan-jankan lola.[3]
Tayo Aderinokun | |
---|---|
Portrait of Tayo Aderinokun | |
Ọjọ́ìbí | Olutayo Aderinokun Oṣù Kàrún 8, 1955 Kano, Kano State, Nigeria |
Aláìsí | 14 June 2011 United Kingdom | (ọmọ ọdún 56)
Ibùgbé | Banana Island, Lagos State, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
Iṣẹ́ | Banker, entrepreneur |
Gbajúmọ̀ fún | Co-Founder of Guaranty Trust Bank |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe<Reflist>
- ↑ "Fola Adeola tribute to Tayo Aderinokun". www.vanguardngr.com. Retrieved 2 December 2016.
- ↑ "Tayo Aderinokun: torrents of accolade on a worthy patron - Vanguard News". vanguardngr.com. 18 September 2011. Retrieved 2 December 2016.
- ↑ "GTBank CEO, Tayo Aderinokun dies in London". www.vanguardngr.com. Retrieved 2 December 2016.