Tayo Oviosu
Tayo Oviosu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ oníṣòwò, tó tún ṣèdásílẹ̀ Paga, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó fàyè gba sísan owó láti orí ẹ̀rọ-alágbèéká wa. Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Paga kọ́kọ́ gbòde.[1][2][3]
Tayo Oviosu | |
---|---|
Oviosu far left in 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Eyitayo David Oviosu Oṣù Kẹ̀sán 10, 1977 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian, American |
Ẹ̀kọ́ | Electrical and Electronics Engineering, University of Southern California Master's degree in Business Administration, Graduate School of Business, Stanford University. |
Iṣẹ́ | Entrepreneur |
Ìgbà iṣẹ́ | 2009–present |
Gbajúmọ̀ fún | Founder and Group CEO of Paga |
Title | Group CEO of Paga |
Olólùfẹ́ | Affiong Williams (m. 2014) |
Website | paga.com/ |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Tara Fela-Durotoye, Tayo Oviosu, Funke Bucknor & more! We present the 10 most powerful Under-40s in Business - #YNaijaPowerList » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-03-31. Retrieved 2019-05-24.
- ↑ "21 Nigerian Tech CEOs at the Top of Their Game". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-04-15. Retrieved 2019-05-24.
- ↑ touch, Chief Chronicler Get in (2017-04-10). "Meet Tayo Oviosu, the man whose financial services company has wider reach than all banks in Nigeria combined". Techpoint.Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-05-24.