Teju Babyface
Teju Babyface ni tun pè ni Gbadewonuola Olateju Oyelakin to jẹ alawada ati ólukọwè ilẹ naigiria[1]. Awọn ọmọ órilẹ ede naigiria ma n pè arakunrin naa ni "Oba sọrọsọrọ"[2]
Teju Babyface | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Gbadewonuola Olateju Oyelakin |
Ìbí | 20 Oṣù Kínní 1979 |
Spouse | Oluwatobiloba Banjoko. O |
Ibiìtakùn | tejubabyface.com |
Igbèsi Àyè Àrakunrin naa
àtúnṣeTeju Babyface ni a bini ọjọ ogun óṣu January, ọdun 1979. Ni ọdun 1999, arakunrin naa bẹre irinajo iṣẹ rẹ lẹyin to kopa ninu ere agbelewo ti óludari Tade Ogidan "Diamond king". Ni ọdun 2001, Teju kopa ninu ere agbelewo "One Too Much". Ni ọdun 2010, Oyelakin da "Teju Babyface show silẹ to si ti gbalejo óriṣiriṣi awọn eyan jakan jakan[3][4].
Ni ọdun 2017, Teju ni a fi jẹ ambassador ti United Nations Sustainable Development Goals[5].
Ni óṣu September ọdun 2012, Oyelakin fẹ Oluwatobilọba Banjoko.o.Ni ọdun 2018 ni wọn bi ibeji[6][7][8].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.bellanaija.com/2010/05/watch-out-leno-letterman-late-night-births-in-nigeria-the-teju-babyface-show-debuts-on-silverbird-tv/
- ↑ https://web.archive.org/web/20140219145630/http://dailyindependentnig.com/2013/09/teju-baby-face-the-nigerian-youth-and-the-rest-of-us/
- ↑ https://punchng.com/im-not-fulfilled-at-this-stage-in-my-life-teju-babyface/
- ↑ https://thewillnigeria.com/news/teju-baby-face-seeks-greener-pastures-in-the-us/
- ↑ https://thenationonlineng.net/the-power-of-giving/
- ↑ https://saharaweeklyng.com/comedian-teju-baby-face-welcomes-twins-with-wife-after-6-years/
- ↑ https://web.archive.org/web/20140203053530/http://www.punchng.com/entertainment/life-beat/teju-babyface-heads-for-the-altar/
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2018/04/976566/