Terry Pheto
Moitgeri Pheto (bíi ni ọjọ́ kọkànlá oṣù karùn-ún ọdún 1981) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà, ó gbajúmọ̀ fún ipá Miriam tí ó kó nínú eré Tsotsi[1]
Terry Pheto | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Moitheri Pheto 11 Oṣù Kàrún 1981 Evaton, South Africa |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–present |
Iṣẹ́
àtúnṣeLẹ́yìn farahàn nínú ere Tsotsi, Pheto tí kópa nínú orísìírísìí eré míràn bíi Catch a Fire(2006), Goodbye Bafana (2007) àti How tó steal 2 Million (2012). Ni oṣù keje ọdún 2008, òun ni ó ṣe ojú fún L'Oréal. Ó ti farahàn nínú orísìírísìí ìwé ìròyìn bíi Destiny, Vanity Fair, Drum, You/Huisgenoot, Y-Magazine, Bona, Heat, Elle, Cosmopolitan, Marie Claire ati True Love. Ó gbà ẹ̀bùn láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Awards.[2]
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣe- Tsotsi (2005)
- Catch a Fire (2006)
- Day and Night (2006)
- Goodbye Bafana (2007)
- Mafrika (2008)
- The Bold and The Beautiful (2011)
- How to Steal 2 Million (2012)
- Mandela: Long Walk to Freedom (2013)
- Cuckold (2015)
- A United Kingdom (2016)
- Madiba TV series (2017)
- What's The Deal (2018-)
Àwọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Terry Pheto: Bold and Beautiful". Independent Online. 29 June 2011. http://www.iol.co.za/tonight/tv-radio/terry-pheto-bold-and-beautiful-1.1090696#.UK1fydd559Y. Retrieved 21 November 2012.
- ↑ "'How to Steal 2 Million' emerges Africa's best film". Africa Review (Nation Media Group). 24 April 2012. Archived from the original on 15 December 2017. https://web.archive.org/web/20171215111100/http://www.africareview.com/Arts+and+Culture/South+African+film+feted+in+Lagos/-/979194/1392664/-/3k9gciz/-/. Retrieved 21 November 2012.