Tertius Zongo (ojoibi 18 May 1957[1]) ni Alakoso Agba orile-ede Burkina Faso lati June 2007.

Tertius Zongo
Prime Minister of Burkina Faso
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
11 June 2007
ÀàrẹBlaise Compaoré
AsíwájúParamanga Ernest Yonli
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kàrún 1957 (1957-05-18) (ọmọ ọdún 67)
Koudougou, Upper Volta
Ẹgbẹ́ olóṣèlúCDP