Teslim Folarin
Olóṣèlú
Teslim Folarin (ojoibi October 1963) je Alagba ni Ile Alagba Asofin Naijiria lati 2003 de 2007.
Teslim Folarin | |
---|---|
Alagba fun Aringbangan Oyo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2007 | |
Asíwájú | Brimmo Yusuf |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | October 1963 Oyo State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Esun isekupani
àtúnṣeNi 4 January, 2011 Oloopa Naijiria fesun kan Folarin ati awon meta miran, Ramoni Jayeoba, Bankole Olaide Raji ati Raimi Ismaila pe won lowo ninu iku Eleweomo,[1][2] to je olori egbe kan NURTW eka Ipinle Oyo.
Ni 13 January 2011, Oloopa Naijiria fagile esun isekupani ti won fi kan bi be Ile-Ejo ni Ibadan tu sile kuro latimole.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Ola Ajayi (5/1/2011). "ELEWEOMO: Sen Folarin arraigned for murder". Vanguard Online Edition. Retrieved 5-1-2011. Check date values in:
|access-date=, |date=
(help) - ↑ Tunde Sanni (05 January, 2011). "Murder: Senate Leader Remanded in Prison". Thisday Online. Archived from the original on 2011-01-07. Retrieved 05 January, 2011. Check date values in:
|access-date=, |date=
(help) - ↑ "Police withdraw murder charges against Folarin".