Thabo Mbeki
Thabo Mvuyelwa Mbeki tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 1942 (18 June, 1942) jẹ́ Ààrẹ àná orílẹ̀-èdè Guusu Áfíríkà láti ọdún 1999 títí dé 2008.
Thabo Mvuyelwa Mbeki | |
---|---|
President of South Africa | |
In office 14 June 1999 – 24 September 2008 | |
Deputy | Jacob Zuma Phumzile Mlambo-Ngcuka |
Asíwájú | Nelson Mandela |
Arọ́pò | Kgalema Motlanthe |
Deputy President of South Africa | |
In office 10 May 1994 – 14 June 1999 Serving with Frederik Willem de Klerk (10 May 1994 – 30 June 1996) | |
Ààrẹ | Nelson Mandela |
Asíwájú | Position established |
Arọ́pò | Jacob Zuma |
Secretary General of Non-Aligned Movement | |
In office 14 June 1999 – 25 February 2003 | |
Asíwájú | Nelson Mandela |
Arọ́pò | Mahathir bin Mohamad |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kẹfà 1942 Idutywa, South Africa |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Ẹgbẹ́ òṣèlú African National Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Zanele Dlamini |
Alma mater | University of London University of Sussex |
Signature |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |