The 48 Laws of Power
'
Fáìlì:GreeneRobert-48LawsOfPower.jpg | |
Olùkọ̀wé | Robert Greene |
---|---|
Country | United States |
Subject | Self-help |
Published | 1998 (Viking Press) (HC); 2007 (HighBridge Audio) CD |
Pages | 480 |
ISBN | Àdàkọ:ISBNT (HC); ISBN 978-1598870923 (CD) |
OCLC | 39733201 |
303.3 21 | |
LC Class | BD438 .G74 1998 |
Followed by | The Art of Seduction |
Òfin agbára méjìdínláàádọ́ta ' (The 48 Laws of Power) (1998) jẹ́ ìwé àpilẹ̀kọ oníṣìípayá tí oǹkọ̀wé Amẹ́ríkà kan tí orúkọ rẹ ń jẹ́ Robert Greene kọ ní ọdún 1998.[1] Ìwé yìí jẹ́ ìkan lára àwọn ìwé tí New York Timee tà wàràwàrà,[2][3] iye tí wọ́n ta jẹ́ mílíọ̀nù kan léní igba ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà;[4] À̀wọn tí wọ́n ti lọ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n rí àti àwọn ìlúmọ̀ọ́ọ́ká ni àwọn àpẹẹrẹ tí òǹkọ̀wé náà lò nínú ìwé rẹ̀.[4][5][6][7][8]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Greene, Robert (2000). The 48 Laws of Power. New York. pp. 452. ISBN 0140280197.
- ↑ "Business Bestsellers". New York Times. November 8, 1998.
- ↑ Green, Hardy. "Best Selling List". BusinessWeek.
- ↑ 4.0 4.1 Chang, Andrea. American Apparel's in-house guru shows a lighter side. LA Times. August 30, 2011.
- ↑ Blake, John. How to Master the ‘48 Laws of Power’. CNN. March 15, 2010.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedOutlawCulture
- ↑ Tice, Carol. All’s Fair?. Entrepreneur. November 1, 2006.
- ↑ Paumgarten, Nick. Fresh Prince. New Yorker. November 6, 2006.