The Empty Man (fíìmù)
The Empty Man jẹ́ fíìmú odùn 2020 abámí tì ùn baani lèrú olúko áti olúdarì ré jè David prior (director)David Prior nìpa éya ré [directorial debut],tì Cullen Bunn áti Vanesa R. Del Rey's íwè tì ò jè orùko pélù fíìmú[The Empty Man] tì awon Boom! Studios si téjàde.Áwon gbájùmọ́ ósérè fíìmú naa James Badge Dale, Marin Ireland,Stephen Root,Ron Canada,Robert Aramayo,Joel Courtney and Sasha Frolova. Òdàlèlòrì enitì òti fì ígbá kan jé ólòpá ri tì òṣìṣẹ́ ìwádìí nìpa ọmọ òbírin ,tì o sì ṣe ìwádìí ri ẹgbè íkókó kan.
The Empty Man | |
---|---|
Adarí | David Prior |
Olùgbékalẹ̀ | |
Òǹkọ̀wé | David Prior |
Àwọn òṣèré | |
Orin | |
Ìyàwòrán sinimá | Anastas Michos |
Olóòtú |
|
Ilé-iṣẹ́ fíìmù |
|
Olùpín | 20th Century Studios |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 137 minutes |
Orílẹ̀-èdè | |
Èdè | English |
Ìnáwó | $16 million[2] |
Owó àrígbàwọlé | $4.8 million[3][4] |
Wọn kọ̀kọ̀ se àgbéyewó nii August 2017 bíi fíìmú àgbáyé láàrin United States, South Africa, àti France, fíìmú náà gbà marki kékeré níí [test screening] àti 20th Century Fox wọn sí sọ ìgbàgbọ nu nínú fíìmú náà gbagbo. Ìkẹyìn fíìmú na sì jáde lórí ítágè ní united states ọjọ 23 ní oṣù october 2020 ti awọn èyán o sì tún gbà tí è. Ọ pàdé jáde ní àrin lasigbo COVID-19, fíìmú náà sì wọ $4 million kárí ayé tí a kosile bugeti rẹ je $16 million. Fíìmú náà sì gba ẹgàn púpò lówó àwon àwòrán nìpa tọ ọja dé náà. Íwóràn rẹ sì yato nigba ti ọ dé home media àti streaming service.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "The Empty Man". letterboxd. Retrieved June 6, 2021.
- ↑ Adam Nayman (May 3, 2021). "Everything Zen: David Prior on "The Empty Man"". Mubi. Retrieved August 25, 2021.
- ↑ "The Empty Man (2020)". Box Office Mojo. Retrieved March 21, 2021.
- ↑ "The Empty Man (2020)". The Numbers. Retrieved December 23, 2020.