The Fish Statue, Epe
Itan
àtúnṣeEre Eja, ti won n pe ni Eja, Epe ni ifowosi, je ere eja nla meji, ti ijoba ipinle Eko gbe kale si Lekki-Epe orita meta ni Epe, Eko, ere naa wa sori nla onigun merin pelu oro naa. "EPE" ni ẹgbẹ rẹ.[1][2]
Ojo kejo osu kokanla odun 2017 ti Gomina ipinle Eko nigba naa, Akinwunmi Ambode, ti won se agbebon Hamza Attah se afihan asa Epe gege bi ile ise ipeja ati wipe arabara naa se afihan Epe asiko yii gege bi ibi ti eja n gbe jade ni ilu Eko, o si so pe ipeja jẹ iṣẹ akọkọ ti awọn ọmọ abinibi.[3]
Itoka
àtúnṣe- ↑ Lagos unveils iconic fish statue in Ambode's hometown - Punch Newspapers (punchng.com)
- ↑ UNVEILING OF THE FISH STATUE AT EPE – Lagos State Government
- ↑ Ambode celebrates founding fathers of Lagos with fish statue | The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News — Saturday Magazine — The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News