The Guardian jẹ́ Ìwé ìròyìn olójoojúmọ́ tí àtẹ̀jáde rẹ̀ ń wáyé ní Ìlú Èkó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ilé iṣẹ́ Guardian Newspapers Limited ni ó ń ṣakápò rẹ̀.[1][2]

The Guardian
Guardian logo.png
TypeÌwé ìròyìn olójoojúmọ́
PublisherGuardian Newspapers Limited
FoundedỌdún 1983
HeadquartersÌlú Èkó
Official websitehttp://www.guardian.ng/

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe