The Harvesters jẹ fiimu 2018 agbejade ti ere idaraya ti Etienne Kallos ko ti otunsi daari, kariaye ti o ṣe ti a kọ ati oludari nipasẹ Etienne Kallos . Won Ṣeto ni igberiko South Africa, fiimu naa tẹle wiwa sojo ori Janmo, omo dun meedogun, ti ogbudo koju afikun ojiji titun inu ebi re peelu fifese ti o sooji ninu re.

Eto ati itan seyo nipasẹ awọn irin-ajo Kallos lo si ayika agbegbe Ila-oorun orilẹ-ede ti o jinna ati awọn ibapade rẹ pẹlu awọn idile to n dako nibẹ. Fiimu naa jẹ ere-idaraya ọpọlọ ti o se afihan awọn akori ti idarapo, idanimọ lako abi labo, ati iwa akọ.[1][2]

Fiimu naa ṣe afihan ni ipaala <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Un_Certain_Regard" rel="mw:ExtLink" title="Un Certain Regard" class="cx-link" data-linkid="92">Un Certain Regard</a> ti odun <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/2018_Cannes_Film_Festival" rel="mw:ExtLink" title="2018 Cannes Film Festival" class="cx-link" data-linkid="93">2018 Cannes Film Festival</a>.

Ahunpo Itan

àtúnṣe

Ile South Africa, ẹkun Ipinle Ofe, ibi agbara ti o daawa fun awon aṣa ẹlẹya funfun Afrikaans. Ni agbegbe idaako fun tara wa ti o ni ife afeeju fun agbara ati ise ako ọkunrin, Janno ( <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Brent_Vermeulen" rel="mw:ExtLink" title="Brent Vermeulen" class="cx-link" data-linkid="98">Brent Vermeulen</a> ) yatọ, oferan aṣiri, kosi lagbara ẹdun okan. Lọ́jọ́ kan, ìyá rẹ̀ (Juliana Venter), tó jẹ́ ẹlẹ́sìn líle, mú Pieter (Alex van Dyk) wá sílé lati dabobo,Pieter je ọmọ òrukàn tigboro tó je olokan líle, ó sì ní kí Janno mu àjèjì yìí gege bi arákùnrin re. Awọn ọmọkunrin meji bẹrẹ ija fun agbara, ogun ati ifẹ obi. [3]

Awon Osere

àtúnṣe

Ṣiṣejade

àtúnṣe

Iwe afọwọkọ fiimu naa jeyo lati inu ifẹ Kallos lati ṣawari ọdọ nipasẹ awọn ti abi leyi ijoba eleyameya to dopin ni ọdun 1995. O lo owo ẹbun lati ọdọ Kiniun Golden ti o gba ni <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Venice_Film_Festival" rel="mw:ExtLink" title="Venice Film Festival" class="cx-link" data-linkid="117">Venice Film Festival</a> fun fiimu ranpe Akoobi ti odun 2009 (Firstborn (2009)) lati ṣe iranlọwọ fun inawo awọn irin-ajo iwadi si Ipinle Ọfẹ ti Ila-oorun.[4]

Awọn oṣere oludari meji, Brent Vermuelen ati Alex van Dyk, ni a sọ ni agbegbe, pẹlu Vermuelen ti o kopa gege bi asiwaju titi di ọsẹ meji ṣaaju isejade bẹrẹ.

A ya fiimu naa ni Ipinle Ọfẹ pẹlu awọn alabase agbaye ti o wa lati South Africa, Greece, Polandii ati France.[5]

Awọn akọrin Faranse Evgueni ati Sasha Galperine ni o ko ohun orin inu ere na, o si gba Aami Eye ni Cannes Soundtrack Award.

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. "'The Harvesters' ('Die Stropers'): Film Review | Cannes 2018". The Hollywood Reporter (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 16 May 2018. Retrieved 9 July 2019. 
  2. "Die Stropers is the latest South African gay themed film heading to cinemas". MambaOnline - Gay South Africa online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 February 2019. Retrieved 9 July 2019. 
  3. "The 2018 Official Selection". Cannes. 12 April 2018. Retrieved 12 April 2018. 
  4. "Cannes Lineup Includes New Films From Spike Lee, Jean-Luc Godard". Variety. 12 April 2018. Retrieved 12 April 2018. 
  5. The Harvesters, retrieved 9 July 2019 
  6. Dercksen, Daniel (10 March 2019). "Writer-director Etienne Kallos talks about Die Stropers (The Harvesters)". The Writing Studio (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 July 2019. 
  7. Ellaya, Chanelle (30 April 2019). "Behind the scenes of Die Stropers (The Harvesters)". Screen Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 July 2019. 
  1. "'The Harvesters' ('Die Stropers'): Film Review | Cannes 2018". The Hollywood Reporter (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 16 May 2018. Retrieved 9 July 2019. 
  2. "Die Stropers is the latest South African gay themed film heading to cinemas". MambaOnline - Gay South Africa online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 February 2019. Retrieved 9 July 2019. 
  3. The Harvesters 
  4. Dercksen, Daniel (10 March 2019). "Writer-director Etienne Kallos talks about Die Stropers (The Harvesters)". The Writing Studio (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 July 2019. 
  5. Ellaya, Chanelle (30 April 2019). "Behind the scenes of Die Stropers (The Harvesters)". Screen Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 July 2019.