The Netng
The Netng (Nigerian Entertainment Today) tí a tún mọ̀ sí NET jẹ́ ilé-iṣẹ́ ìròyìn ìdánilárayá lórí ẹ̀rọ-ayélujára, tó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Type | Online publication |
---|---|
Owner | ID Africa |
Founder | Adekunle Ayeni |
Publisher | ID Africa |
Founded | November 23, 2009 |
Headquarters | Lagos, Nigeria |
Sister newspapers | 23Star, Neusroom, Orin |
Official website | https://thenet.ng/ |
Ó jẹ́ orísun ilé-iṣẹ́ ìdánilárayá, oge-ṣíṣe, àti ìròyìn nípa ìgbésí ayé ẹ̀dá. [1][2][3] Netng ṣẹ̀dá apá kan NET Newspaper Limited (NNL) títí di ọdún 2019 nígbà tí wọ́n ID Africa gbà á. [4][5] Netng jẹ́ olùṣètò NECLive (Nigerian Entertainment Conference) èyí tó jẹ́ Àpéjọ Eré ìdárayá Nàìjíríà àti the NET Honours. [6][7][8][9]
Ìtàn
àtúnṣeNigerian Entertainment Today (NET) dásílẹ̀ ní ọjọ́ kẹta-lé-lógún oṣù kọkànlá ọdún 2009, nípasẹ̀ Ayeni Adekunle.[10] NET tún ṣiṣẹ́ bí iléeṣẹ́ atẹ̀wétà, ó sì ti ṣe àtẹ̀jáde tó ti kiri mẹ́ta-dín-lọ́gbọ̀n àwọn ìlú pàtàkì Nàìjíríà, ó sì ti tà tó ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá lọ́sọọsẹ̀. [11] Ní ọdún 2016, NET ní díẹ̀ díẹ̀ kẹ́sẹ̀ ilé-iṣẹ́ àtẹ̀jáde rẹ̀ kúrò nílẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ọ̀pọ̀ nínú àwọn òǹkàwé wọn ti sún sí orí ẹ̀rọ ayélujára láti wá àwọn ìròyìn ìdánilárayá. Ní oṣù kẹrin ọdún 2013, ilé-iṣẹ́ ipò ojú òpó wẹ́ẹ̀bù kan, Alexa fún Netng ní ipò kẹ́ta-lé-lọ́gbọ̀n ojú òpó wẹ́ẹ̀bù tí a ṣàbẹ̀wò jùlọ ní Nàìjíríà. [12]
References
àtúnṣe- ↑ "NETNG Executive Editor/COO Jide Taiwo Resigns". https://www.pmnewsnigeria.com/2019/08/14/netng-executive-editor-coo-jide-taiwo-resigns/.
- ↑ "NETng To Announce Nominees For NET Honours on Friday". BrandCrunch Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-19. Retrieved 2020-06-02.
- ↑ "BBnaija housemate's drama during a NETng interview". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-05. Archived from the original on 2021-12-20. Retrieved 2020-06-02.
- ↑ "ID Africa acquires TheNETng to form marketing, media and technology powerhouse". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-04. Retrieved 2020-05-25.
- ↑ OloriSupergal (30 April 2012). "Olori Supergal". Olori Supergal Blog. Retrieved 23 July 2015.
- ↑ "Neclive Organizers unveils new two dah format for 2020". guardian.ng. February 2020. Archived from the original on 2023-09-25. Retrieved 2020-05-25.
- ↑ "NET Honours 2019 unveils nominees". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-14. Retrieved 2020-05-25.
- ↑ "NET Honours Is Back, Winners To Be Revealed At NECLive 2019". BrandCrunch Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-05. Retrieved 2020-05-25.
- ↑ "NET Honours 2019: Here are the nominees | Encomium Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 12 April 2019. Retrieved 2020-05-25.
- ↑ Olori Supergal (26 April 2012). "NET Publisher Shares Success Story".[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "About NET - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily". Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily. 26 February 2015. Retrieved 23 July 2015.
- ↑ "thenet.ng Site Overview". alexa.com. Archived from the original on 13 September 2015. Retrieved 23 July 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)