Christopher George Latore Wallace tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù karùn-ún ọdún 1972, tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kẹta ọdún 1997 (May 21, 1972 – March 9, 1997) jẹ́ olórin tàkasúfèé ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó gbajúmọ̀ bí Biggie Smalls lẹ́yìn tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ (Let's Do It Again) lọ́dún 1975, àti Big Poppa, pẹ̀lú The Black Frank White, bẹ́ẹ̀ náà nínú sinimá àgbéléwò (King of New York),[1] sugbon gangan pelu oruko ori itage re The Notorious B.I.G..

The Notorious B.I.G.
Fáìlì:The Notorious B.I.G.jpg
Wallace in 1995
Ọjọ́ìbíChristopher George Latore Wallace
(1972-05-21)Oṣù Kàrún 21, 1972
Brooklyn, New York, U.S.
AláìsíMarch 9, 1997(1997-03-09) (ọmọ ọdún 24)
Los Angeles, California, U.S.
Cause of deathShooting
Orúkọ míràn
  • Biggie Smalls
  • Biggie
  • Frank White
  • Big Poppa
Iṣẹ́Rapper
Ìgbà iṣẹ́1992 (1992)–1997 (1997)
Olólùfẹ́Faith Evans (1994–1997; his death)
Àwọn ọmọ2 (T'yanna and Christopher Jr.)
Musical career
Irú orin
Labels
Associated acts

Wallace dagba ni adugbo Brooklyn ni Ilu New York.



Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Notorious B.I.G.: In His Own Words, And Those of His Friends Archived 2007-03-11 at the Wayback Machine. (March 7, 2007). MTV News. Accessed 2007-03-11.