The Delivery Boy tó fi ìṣòro ráńpẹ́ hàn tó jẹ́ kíkọ àti gba ìdarí láti ọwọ́ Adékúnlé Adéjùyígbé, Ó jẹ́ Òǹṣe fíìmù. Àwọn gbajúmọ̀ fíìmù náà ni jẹ́ Jammal Ibrahim, Jẹ́mìnà Osunde, Charles Etubiebi, Kẹ́hìndé Fáṣuyì àti àwọn olóòtú mìíràn. Delivery Boy náà di wíwò ní film festivals pẹ̀lú African Film Festival New York,[1] Lights, Camera, Africa,[2] Nollywood Week Paris,[3] the Africa International Film Festival (AFRIFF), Lake International PanAfrican Film Festival, Real Time International Film festival (RTF), àti the 9th Jagran Film Festival. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ oyè bí i "The Best Nigerian Film Award" ní Africa International Film Festival àti "Best Supporting Actor" ní the Real Time International Film Festival (RTF) láti ìgbà tó ti di wíwò láti ọdún 2018.[4]

The Delivery Boy
AdaríAdékúnlé Adéjùyígbè
Òǹkọ̀wéAdékúnlé Adéjùyígbè
Àwọn òṣèré
OrinMichael 'Truth' Ọ̀gúnladé
Ìyàwòrán sinimáNodash
OlóòtúNodash for The Post Office
Ilé-iṣẹ́ fíìmùSomething Unusual Studios
OlùpínSilverbird Distributions
Déètì àgbéjáde2019/05/24
ÀkókòÌṣẹ́jú mẹ́rindínláàádọ́rin
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèHaúsá, Pígìn, Gẹ̀ẹ́sì

Fíìmù náà gba yíya láti ọwọ́ The Elite Film Team, ó jẹ́ Atọ́kùn láti ọwọ́ Something Unusual Studios àti pín káàkiri láti ọwọ́ Silverbird Distributions in Nigeria.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The Delivery Boy | African Film Festival, Inc." (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-18. 
  2. "Nodash's 'The Delivery Boy' applauded at Lights, Camera, Africa". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-01. Retrieved 2021-07-18. 
  3. "Paris Nollywood Week Film Festival 2018 lists films showing". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-04-09. Retrieved 2021-07-18. 
  4. "‘The Delivery Boy’ Film Wins Big At AFRIFF". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-11-23. Archived from the original on 2021-10-16. Retrieved 2021-07-18. 
  5. "Nodash's 'The Delivery Boy' applauded at Lights, Camera, Africa". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-01. Retrieved 2021-07-18.