Thierry Ndikumwenayo (ti a bi ni ọjọ kerindinlogbon osu keta odun 1997) [1] je elere ije olona jinjin orile - ede Burundi. Ni ọdun 2019, o dije ninu mita 10,000 awọn ọkunrin ni Idije Awọn ere-idaraya Agbaye ti 2019 ti o waye ni Doha, Qatar. [1] Ko pari ije re. [1]

Ni ọdun 2014, o gba ami-eye fadaka ni idije mita 3000 ti awọn ọmọkunrin ni Olimpiiki Igba ooru Ọdun 2014 ti o waye ni Nanjing, China. [2]

Ni ọdun 2017, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2017 IAAF World Cross Country Championship ti o waye ni Kampala, Uganda. [3] O pari ni ipo 95th. [3]

Ni ọdun 2019, o dije ninu idije awọn ọkunrin agba ni 2019 IAAF World Cross Country Championships ti o waye ni Aarhus, Denmark. [4] O pari ni ipo 9th. [4] Ni ọdun 2019, o bori idije awọn ọkunrin ni Cross Internacional de la Constitución ti o waye ni Alcobendas, Spain. [5]

Awọn itọkasi

àtúnṣe

Ita ìjápọ

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control