Thishiwe Ziqubu (ti a bi ni ojo karun osu kejo odun 1985) je ako ere, oludari ere ati osere ti owa lati ilu South africa.[1] Won gba ami eye Best Actress in a Supporting Role ni 2016 Africa Movie Academy Awards , fun ipa won gege bi Tashaka ninu ere ife Tell Me Sweet Something.[2] Ni odun 2019, won shey oludari awon ipele kankan ninu MTV Shuga Down South [3]

Thishiwe Ziqubu
Thishiwe Ziqubu n soro nipa sise oludari MTV Shuga ni odun 2019
Ọjọ́ìbí5 August 1985
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
Iṣẹ́oludari ere ati osere

Ziqubu keko nipa kiko ere ati pelu bi a se man dari ere lehin ti o pari ile iwe giga. Lehin na won lo si ile eko African Film and Drama Academy (AFDA), ile eko nipa fiimu[4]. Lehin wa igba na won pari eko nipa sisere ni Los Angeles campusi titi New York Film Academy.[1]

 
Ziqubu ni gba ti on dari Lerato Walaza ati elo miran lori fiimu MTV Shuga

Ziqubu bere ere sise ni odun 2011 ni pase fiimu Man on Ground, eleyi ti o je ki ise ise re sun si waju. Gegebi onkowe ati oludari ere, won ko, won si tun gbe ere kukuru meta jade fun ra won awon fimmu na ni: Out Of Luck, Subdued ati Between the Lines.[1]. Won ti ko ere fun awon fiimu South African television soap opera gege bi Isidingo, Rhythm City ati fun Is'Thunzi . Won ko pa ninu kiko, gbigbejade ati didari supernatural ere dirama eleya merin ti a mosi Emoyeni.[5]

Ni odun 2019, won shey oludari ere elesese MTV Shuga Down South.

Asayan ere

àtúnṣe
Year Title Role
2011 Man on Ground Zodwa
2014 Hard to get Skiets[6]
2015 While You Weren't Looking Shado
2015 Tell Me Sweet Something Tashaka

Awon itokasi

àtúnṣe

Awon linki tita

àtúnṣe