A bí Thomas Hardy (2 June 1840 – 11 January 1928) ní 1840. Ó kú ní 1928. Ó máa ń kọ ìtàn-àròsọ àti ewì. Ọmọ ìlú Dorset ni. Kòlà-kò-ṣagbe sì ni pẹ̀lú. Ó ti di ‘architect’ kí ó tó di 1873. Ó fi iṣẹ́ yìí sílẹ̀ láti máa kọ ìwé. Ó gbà pé akéwì ni òun. Ó kọ tó ẹgbẹ́rún ewì irú èyí tí a máa ń pè ní ‘short lyrics’. Ewì rẹ̀ máa ń kún fún òótọ́ ó sì máa ń mú ènìyàn lára.

Thomas Hardy
Iṣẹ́Novelist, Poet, and Short Story writer
Literary movementNaturalism
SpouseEmma Lavinia Gifford
(1874–1912)
Florence Dugdale
(1914–1928)


Itokasi àtúnṣe