Agbègbè àkókò

(Àtúnjúwe láti Time zone)

Àkókò-agbègbè jẹ́ àwọn àgbègbè ayé tí àkókò wọn papọ̀ tàbí jẹ́ ìkan náà.

Àwọn ìlú tó ní irúfẹ́ àkókò-agbègbè kan náà.