Tobiloba Ajayi
Tobiloba Ajayi jẹ́ agbejọ́rọ̀ ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ní àrùn Cerebral palsy.
Tobiloba Ajayi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Oluwatobiloba Ajayi Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Writer, Lawyer, activist |
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeAjayi ni ọmọ kẹrin láàárín àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ bí. Àwọn òbí rẹ kò kọ́kọ́ fẹ́ ran lọ sí ilé ẹ̀kọ́ nítorí àìlera tí ó ní. Àìlera yí kò fun ni àǹfààní láti lè jókòó, dúró tàbí rìn. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹta. Ó gboyè gíga jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Hertfordshire nínú ìmò òfin àgbáyé.[1]
Iṣẹ́
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ni Mobility Aid and Appliance Research and Development Center.[2] Ó sì wà láàárín àwọn tí ó ṣe òfin fún àwọn alábọ̀ ara ní ìpínlẹ̀ èkó.[3] Ó gbà Mandela Washington Fellowship ni ọdún 2016.[4] [5]Ní oṣù kìíní ọdún 2017, ó si ṣẹ́ pelu Benola Cerebral Palsy Initiatives. Ní oṣù kejì ọdún 2018, ó gbé ètò kàn kalẹ̀ tí ó fi ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọ tí ó bá ní àrùn Cerebral Palsy.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adetorera, Idowu. "‘There is life after disability’". The nation. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Adebayo, Bose. "MAARDEC’s Ms wheelchair contest gives voice to the physically challenged". Vanguard. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Osonuga, Freeman. "A Nigerian Lawyer With Cerebral Palsy: My Encounter". The Huffington Post. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Precious, Drew. "The Presidential Precinct Announces 2016 Mandela Washington Fellows". Presidential Precinct. Retrieved 17 January 2017.
- ↑ Precious, Drew. "Tobiloba Ajayi". Presidential Precinct. Retrieved 16 November 2019.
- ↑ Dark, Shayera (27 February 2018). "Nigerians with disabilities are tired of waiting for an apathetic government". Bright magazine. https://brightthemag.com/health-nigeria-disability-rights-activism-96aa2cfef5f2. Retrieved 11 November 2019.