Toke Makinwa
Toke Makinwa (bii ni ọjọ kẹta oṣu ọkanla ọdun 1984) je omo orile ede Naijiria. O je agbóhùnsáfẹ́fẹ́, ati onkọwe.[4][5][6][7][8] O kọ iwe On Becoming ni odun 2016 ni osu mọkanla. O je adari eto ọkọ owurọ ni ori 93.7 FM.[9][10]
Toke Makinwa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kọkànlá 1984[1] Lagos, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | Federal Government Girls' College and University of Lagos |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati onkọwe |
Olólùfẹ́ | Maje Ayida (m. 2014–2017) [2][3] |
Website | Official website |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeWọn bí Toke Mali wá ní ọjọ́ kẹta oṣù kọkànlá ọdún 1984 sì ìlú Èko ni Ipinle Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Federal Government Girls College ní ìlú Oyo, Ibadan Makinwa lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos ni ibi tí ó ti kà English and Literature.
Iṣẹ́
àtúnṣeNí ọdún 2010, Makinwa kọ́kọ́ fi ara rẹ hàn ní orí ẹ̀rọ agbohun sì afẹ́fẹ́ tí Rythm 93.7 Fm ni ori eto ọkọ ÒWÚRỌ̀.[11] Ní ọdún 2012, ó ṣe atọkun ètò Obìnrin tí ó rẹwà jùlo ni ìpínlè Nàìjíríà.[12][13] Óun pelu Tosyn Bucknor àti Oreka Godis jọ ṣe atọkun fún ètò Flytime TV's Live Chicks.[14] Ni ọdún 2012 yí náà ni ò béèrè eto Toke Moments ní orí YouTube vlog.[15][16] Ní ọdún 2014, Hip Hop World Wide Magazine kéde Makinwa gẹ́gẹ́ bí atọkun ètò Ifọrọwanilẹnuwo àti ọ̀rọ̀ ile ise won.[17][18] Ó gbà ìṣe gẹ́gẹ́bí ìkàn lára àwọn atọkun ètò ni ilu ìṣe Ebony Tv fún ètò Moments.[19]
Makinwa tí se atọkun ètò fun ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò bíi Future and City People Award ni odun 2013 àti Headies Award ni ọdún 2014.[20][21] Makinwa kọ ìwé On Becoming ni osu kọkànlá ọdún 2016. Ìwé na sọ̀rọ̀ nípa ìsòro tí ó ní àti tí ọkọ rẹ ṣe já kú ń lẹ̀.[22][23][24] Makinwa lọ ká kiri àwọn ìlú bí South Afrika, U.S.A, U.K àti àwọn ìlú miiran ni ilẹ̀ Áfíríkà láti tá ìwé náà.[25][26][27][28] Ní ọdún 2017, ó tún kọ ìwé miiran tí ó pè àkòrí rẹ ni Handbag line.[29][30][31]
Ní ọdún 2013, Makinwa jẹ́ asojú fún ilé ìṣẹ́ United Africa Company Of Nigeria, òun pelu Osas Ighodaro, Dare Art Alade, àti Dan Foster.[32]
Ilé ìṣẹ́ olówó iyebíye tí Nestle ni Ipinle Nàìjíríà fi ṣe ojú ọjà Maggi.[33]Ní odùn 2016, ó di asoju fún ilé ìṣẹ́ Mecran Cosmetics.[34] Òun sì ní asojú fún ilé ìṣẹ́ Payporte[35] àti Ciroc.[36]
Ayé rẹ̀
àtúnṣeMakinwa se ìgbéyàwó pẹlu Maje Ayida ní ọjọ́ Kàrún dínlógún oṣù kìíní ọdún 2014, olólùfẹ́ rẹ fún ọdún mẹjọ.[37] Ní ọdún 2015, ó pínyà pelu Ayida lẹ́yìn tí ó rí wípé ó ti fún ẹlòmíràn lóyún.[38][39][40] Ní ọjọ́ Kàrún osù Kẹ̀wá ni ilé ẹjọ́ tún ìgbéyàwó náà kà ni ìpínlè èkó lórí pé Ayida ṣe àgbèrè.[41][42]
Ẹ̀bùn
àtúnṣeYear | Award | Category | Result | Notes |
---|---|---|---|---|
2012 | The Future Awards [43][44] | On Air Personality of the Year (Radio) | Yàán | [45] |
2013 | Nigeria Broadcasters Awards [46] | Outstanding Female Presenter of the Year | Gbàá | |
2013 Nigeria Entertainment Awards | Radio OAP of the Year | Wọ́n pèé | ||
2014 | Nickelodeon Kids' Choice Awards [47] | Favourite Nigerian On Air Personality | Yàán | [48] |
2014 Nigeria Entertainment Awards | Entertainment Personality of the Year | Wọ́n pèé | ||
Best OAP of the Year | Wọ́n pèé | |||
2014 | ELOY Awards[49] | TV Presenter of the Year & Brand Ambassador (Maggi) | Wọ́n pèé | N/A |
2017 | Glitz Awards[50] | Style Influencer of the Year | Gbàá | |
2017 | Avance Media[51] | Most Influential Young Nigerian in Media | Gbàá | |
2018 | Africa Youth Award[52] | 100 Most Influential Young Africans[53] | Gbàá |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Happy Birthday to OAP; Toke Makinwa". Daily Times of Nigeria. 3 November 2014. Retrieved 4 November 2014.
- ↑ "Photos: Toke Makinwa & Maje Ayida’s Official Wedding Pictures". lailasblog.com. 21 January 2014. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 8 October 2017.
- ↑ "Court finally dissolves Toke Makinwa’s marriage". lailasblog.com. 6 October 2017. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 6 October 2017.
- ↑ "Watch Toke Makinwa's Vlog of the week". bellanaija.com. 18 June 2014. Retrieved 17 July 2014.
- ↑ "My relationship with Maje Ayida over- Toke Makinwa". punchng.com. Archived from the original on 2 June 2014. Retrieved 2 June 2014.
- ↑ "My Wedding Idea came when I was 5". punchng.com. Archived from the original on 5 June 2014. Retrieved 2 June 2014.
- ↑ "Toke Makinwa wins Best OAP of the year". Archived from the original on 2 June 2014. Retrieved 2 June 2014.
- ↑ "Toke Makinwa launches skincare product 'Glow by TM'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-13. Retrieved 2019-03-31.
- ↑ Mix, Pulse. "Toke Makinwa's Vlog: Toke Moments : Marriage & the Unnecessary Pressure from Society". pulse.ng. Archived from the original on 30 June 2016. Retrieved 30 May 2016.
- ↑ "Read Toke Makinwa’s ‘On Becoming’ book: Why Maje didn’t get her pregnant, begged her for money & more". lailasblog.com. 28 November 2016. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 8 October 2017.
- ↑ "'You are totally fake' - Toke Makinwa's Rhythm FM co-host lashes out » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-22. Retrieved 2019-03-31.
- ↑ "Toke Makinwa", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2019-03-27, retrieved 2019-03-31
- ↑ "Toke Makinwa and Chris Okenwa to host MGBN 2012". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-05-01. Retrieved 2019-03-31.
- ↑ Says, Weapon (2013-03-04). "Toke Makinwa explains her absence on 3 Live Chicks". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31.
- ↑ "It is laughable to say I have a child –Toke Makinwa". Punch Newspapers.
- ↑ MGA1 (2019-02-01). "Watch A New Episode Of Toke Makinwa‘s ‘Toke Moments’". MediaGuide.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-03-27. Retrieved 2019-03-31.
- ↑ Hip TV (2014-11-05), TRENDING HOST TOKE MAKINWA GETS SPECIAL BIRTHDAY TREAT (Nigerian Entertainment News), retrieved 2019-03-31
- ↑ BellaNaija.com (2014-01-10). "Toke Makinwa to Host New Show “Trending” on Hip TV | To Debut this January". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31.
- ↑ "Toke Makinwa To Get Her Own TV Show". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-01-10. Retrieved 2019-03-31.
- ↑ BellaNaija.com (2013-12-20). "Toke Makinwa & Vector to Host the 2013 Future Awards Tonight in Port Harcourt". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31.
- ↑ BellaNaija.com (2014-09-18). "Bovi & Toke Makinwa are the Hosts of the 2014 Headies!". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31.
- ↑ "How gas cylinder explosion killed Toke Makinwa's parents". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-11-29. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Read 10 Shocking Revelations From Toke Makinwa's Book, 'On Becoming' | Nigerian Celebrity News + Latest Entertainment News". stargist.com. Archived from the original on 2019-03-27. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ Augoye, Jayne (2017-10-06). "Toke Makinwa, Maje Ayida finalise divorce". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01.
- ↑ MediaGuide (2016-11-29). "Just One Day After Launch, Toke Makinwa Becomes Amazon's Best Selling Author". MediaGuide.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-06-15. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ BellaNaija.com (2016-12-20). "Toke Makinwa’s “On Becoming” Book Launch in Abuja was so Emotional! See all the Photos on BN". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Toke Makinwa Takes Her Book Tour To Kenya Despite Her Estranged Husband's Threat To Sue - Gistmania". www.gistmania.com. 2017-02-09. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ KOKO (2017-06-27). "Photos From Toke Makinwa's 'On Becoming' South Africa Book Tour". KOKO TV Nigeria | Nigeria News & Breaking Naija News. Archived from the original on 2021-10-28. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ BellaNaija.com (2017-11-03). "EXCLUSIVE: #BabyGirlForLife! Toke Makinwa launches Luxury Bag Line". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Laura Ikeji Set To Buy Toke Makinwa’s Bag". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-29. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Toke Makinwa launches skincare product 'Glow by TM'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-13. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Toke, Foster & Osas becomes Lipton ambassandors". bellanaija.com. 17 June 2013. Retrieved 7 June 2014.
- ↑ "Tiwa savage , Toke Makinwa bag mouth watering deals!". Vanguard News. 11 April 2014.
- ↑ "TOKE MAKINWA IS THE NEW BRAND AMBASSADOR FOR MECRAN COSMETICS…GET THE SCOOP!". Archived from the original on 10 June 2016. Retrieved 30 May 2016.
- ↑ "Tayo Faniran, Toke Makinwa unveiled as Payporte ambassadors". Vanguard News. 29 January 2015.
- ↑ "Toke Makinwa becomes the first female ambassador for Ciroc in Nigeria". Olori Supergal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-27. Archived from the original on 2019-04-01. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Toke and Maje surprise wedding ceremony". bellanaija.com. Retrieved 7 June 2014.
- ↑ "I’ll quit if I’m unhappy in next marriage - Toke Makinwa". Vanguard News. 8 August 2019.
- ↑ "Rhthymn 93.7 OAP, Toke Makinwa and Maje Ayida cancel engagement". 27 August 2012.
- ↑ "Toke Makinwa’s Husband, Maje Makes First Public Appearance ‘ALONE’ Weeks After Marriage Crisis - INFORMATION NIGERIA". INFORMATION NIGERIA. Retrieved 30 May 2016.
- ↑ Augoye, Jayne (6 October 2017). "Toke Makinwa, Maje Ayida finalise divorce - Premium Times Nigeria".
- ↑ "Court finally dissolves Toke Makinwa’s marriage". lailasblog.com. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 6 October 2017.
- ↑ "Toke Makinwa nominated for Future Awards". Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 6 June 2014.
- ↑ Damilare Aiki (18 July 2012). "Future Awards nominees unveiled". bellanaija.com. Retrieved 6 June 2014.
- ↑ "2012 Future Awards Winners". jaguda.com. Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 6 June 2014.
- ↑ "Nigeria Broadcasters Awards list of winners". bellanaija.com. 12 December 2013. Retrieved 6 June 2014.
- ↑ "Nickelodeon Kids Choice Awards nominees". bellanaija.com. 25 February 2014. Retrieved 6 June 2014.
- ↑ "Toke Makinwa, Toolz and others for Nicklelodeon Kids Choice Awards". informationng.com. 26 February 2014. Retrieved 6 June 2014.
- ↑ "Exquisite Lady of the Year (ELOY) Awards Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Archived from the original on 3 July 2017. Retrieved 20 October 2014.
- ↑ BellaNaija.com (2017-08-20). "Toke Makinwa wins Style Influencer of the Year at Glitz Style Awards 2017". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01.
- ↑ pakpah. "Toke Makinwa voted 2017 Most Influential Young Nigerian in Media" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-07-02. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ Amodeni, Adunni (2018-09-07). "Falz, Davido, Ahmed Musa listed among 100 most influential young Africans". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-04-01. Retrieved 2019-04-01.
- ↑ "Davido, Toke Makinwa. Mohammed Salah, Falz named on 100 most influential young Africans list". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-06. Retrieved 2019-04-01.