Toluse Olorunnipa
Ajábọ̀-ìròyìn ní Amẹ́ríkà
Tolúṣẹ "Tolú" Ọlọ́runnípa (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kejìlá ọdún1986) jẹ́ ẹ̀yà American-Nigerian oníròyìn olú-ilé-iṣẹ́ ìṣèjọba orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà (White House) àti akọ̀ròyìn orí tẹlifíṣọ̀ọ̀nú. Òun ni oníròyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí ó ṣiṣẹ́ ó oníròyìn Olú-ilé-iṣẹ́ ìṣèjọba orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà, White House.
Tolúṣẹ Ọlọ́runnípa | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kejìlá 1986 |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Stanford University (BA, Sociology; MSc in Sociology |
Title | Correspondent, CBS News, CNN News |
Website | [1] |
Ó ṣiṣẹ́ ìròyìn fún Washington Post àti onílámèyítọ́ (analyst) fún CNN. Ó ti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Bloomberg News, Miami Herald, àti àwọn ìròyìn Stanford.
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeOlorunnipa jáde ni Ile-ẹkọ giga Stanford níbi tí ó ti ṣe Sociology lẹ́yìn náà ó gboyè Msc rẹ̀ ní Ilé-ẹ̀kọ́ gíga kan náà.