Toni Tones

Akọrin obìnrin

Gbemi Anthonia Adefuye ti oruko inagi re je Toni Tones je osere, agohunsafefe ati ayaworan[1] [2]ni orile ede Naijiria.

Toni Tones
on NdaniTV
Ọjọ́ìbíGbemisola Anthonia Adefuye
Orílẹ̀-èdèNigeria
Ẹ̀kọ́Queen's College, Lagos
University of Lancaster
Iṣẹ́
  • Media personality
  • actress
  • photographer
  • singer
Websitewww.tonitones.com

Won bii ni osu keje, o si je abikeyin ninu awon omo marun ti awon obi re bi. O lo si ile eko Queen's College. O gboye ninu eko itaja ati isiro ni ile eko giga ti University of Lancaster ni orile ede United Kingdom.[3] Leyin ti o pari eko re, o dari pada si orile ede Naijiria ni odun 2009.

O farahan gege bii osere ninu ere Gidi-Culture.[4] O ti kopa ninu awon ere bii What Lies Untold (2015),U-turn, It's Her Day (2016)[5], Rumour Has It (2016), Head over Heels (2017), 5th Floor (2017), Royal Hibiscus Hotel (2017), June (2017), King of Boys (2018)[6] ati Lara and the Beat[7].

Awon Itokasi

àtúnṣe
  1. Why I'm passionate about photography, SunNewsOnline, Retrieved 6 July 2017
  2. New photos of Toni Tones, BellaNaija.com, Retrieved 6 July 2017
  3. Nobody Believed in My Music, YNaija.com, Retrieved 7 July 2017
  4. "Toni Tones - Profile". duchessinternationalmagazine.com/profile/toni-tones/. 12 May 2016. Retrieved 7 July 2017. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. "Wedding Movie "It’s Her Day" starring Bovi, Adunni Ade, Toni Tones, Omoni Oboli & more Premieres on Friday September 9! - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-07-07. 
  6. Cable Lifestyle (2 May 2018). "Boys’ teaser reveals little but will keep you in suspense". The Cable Nigeria. https://lifestyle.thecable.ng/kemi-adetiba-king-of-boys-teaser/. Retrieved 29 October 2018. 
  7. "Why I Don’t Play Sexual Roles – Toni Tones | Independent Newspapers Nigeria" (in en-GB). Independent Newspapers Nigeria. 2018-08-17. https://www.independent.ng/why-i-dont-play-sexual-roles-toni-tones/.