Tony Onyemaechi Elumelu (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta ọdún 1963) jẹ́ pàràkòyí oníṣowò, onímọ̀ ètò ọ̀rọ̀ ajé ati afowóṣàánú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Alága àti olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ Heirs Holdings,Transcorp at ilé ìfowópamọ́ the United Bank for Africa. Bẹ́ẹ̀ náà òun ni olùdásílẹ̀ Tony Elumelu Foundation, àjọ olùrànlọ́wọ́-aláìlérè, tí ń ran àwọn) ọ̀dọ́ lọ́wọ́ láti dá okowò ara wọn sílẹ̀. Ibi tí ó ṣàánú dé pẹ̀lú akitiyan rẹ̀ fún ìdàgbàsókè Nàìjíríà, ìjọba àpapọ̀ dá a Kọ́lá pẹ̀lú oyè "the Commander of the Order of the Niger (CON)" àti "Member of the Order of the Federal Republic (MFR)" lọ́dún 2003. Wọ́n bí ọlá fún un gẹ́gẹ́ bí ẹni tó wà ní ipò ogún nínú àwọn tó lágbára jùlọ nílẹ̀ Áfíríkà.[2] [3] [4]

Tony O. Elumelu
MFR, CON
Ọjọ́ìbíAnthony Onyemaechi Elumelu
22 Oṣù Kẹta 1963 (1963-03-22) (ọmọ ọdún 61)
Jos, Plateau, Nigeria
IbùgbéLagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian (1963–present)
Iléẹ̀kọ́ gígaAmbrose Alli University,
University of Lagos, Lagos

Delta State University.

Benue State University
Iṣẹ́Chairman, Transnational Corporation of Nigeria, Heirs Holdings & United Bank for Africa
Ìgbà iṣẹ́1987—present
Notable workTony Elumelu Entrepreneurship Programme
Net worthUS$700 million (March 2015)[1]
Olólùfẹ́Dr. Awele Elumelu
Parent(s)
  • Dominic Elumelu (father)
  • Suzanne Elumelu (mother)
Àwọn olùbátanNdudi Elumelu (brother)

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Tony Elumelu" at Forbes.
  2. "Tony Elumelu". Forbes. 2019-08-14. Retrieved 2019-12-03. 
  3. "Empowering African Entrepreneurs". The Tony Elumelu Foundation. 2018-08-16. Retrieved 2019-12-03. 
  4. Udodiong, Inemesit (2019-01-08). "Tony Elumelu: From salesperson to successful entrepreneur, the inspiring story of Nigerian billionaire". Google. Retrieved 2019-12-03.