Tony Momoh
Ọmọ oba Tony Momoh (tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣu kẹrin ọdún 1939, tó sì kú ní ọjọ́ kínní oṣù kejì ọdún 2021)[1] jẹ́ akọ̀ròyìn Nàijíríà àti olóṣèlú kan tí ó jẹ́ Mínísítà fún Ìfitónilétí àti Àṣà Nàijíríà (láti ọdún 1986 wọ 1990) lákòókò ìjọba ológun ti Ọ̀gágun Ibrahim Babangida.
Prince Tony Momoh | |
---|---|
Minister of Information and Culture | |
In office 1986–1990 | |
Arọ́pò | Alex Akinyele |
Chairman, Congress for Progressive Change | |
In office January 2011 – 1 February 2021 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Auchi, Colonial Nigeria | 27 Oṣù Kẹrin 1939
Aláìsí | 1 February 2021 | (ọmọ ọdún 81)
Website | http://www.tonymomoh.com |
Ìbí àti ẹ̀kọ́
àtúnṣeA bí Momoh ní ọjọ́ 27 Oṣù Kẹrin ọdún 1939 ní Auchi, ìjọba ìpínlẹ̀ Edo. Ó jẹ́ ọmọ karùn-ún lé lọ́gọ́jọ (165) ti Ọba Momoh I ti Auchi.[2]
Ó lọ sí Ilé-ìwé Ìjọba Auchi (1949–1954) àti Ilé-ìwé Anglican Okpe (1954). Momoh jẹ́ Olùkọ́ni Akẹ́ẹ̀kọ́ ní Ilé-ìwé Anglican, Auchi (Oṣù kińní- Oṣù kejìlá 1955) ati Olukọni ni Ile-iwe Anglican, Ubuneke, Ivbiaro, Ijọba Ibile Owan (January 1958 - Kejìlá 1959).[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Iniobong, Iwok (1 February 2021). "Life and times of Tony Momoh". BusinessDay.ng. Archived from the original on 1 February 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "OBITUARY: Tony Momoh, the 165th child of Edo monarch who defended Buhari till he died". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2 February 2021. Retrieved 2021-07-09.
- ↑ "Biography – Positions held before being a Journalist". Tony Momoh. Retrieved 18 June 2011.