Tonye Garrick
Aránṣọ
Tonye Garrick (tí a bí ní 27 August 1983) tí òpòlopò ènìyàn mò sí Tonye jẹ́ olorin ọmọ orílè-èdè Naijiria tí a bí bi sí orílè-èdè England. [1] Orin accapella rè pèlú akole "what about us?"(tí ó ko ní odun 2010) ni wọ́n lò níbi ìjíròrò Ààrẹ Ọ̀dọ́ Nàìjíríà lọ́dún 2011. [2] Ófi isé rè kalè gégé bi olubadamoran òwò ní odun 2013 láti bèrè orin kiko [3]
Tonye | |
---|---|
lóri NdaniTV | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Tamunotonye Nneka Nkiruka Ibiyemi Garrick |
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kẹjọ 1983 England |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) | Singer-songwriter, fashion and interior designer |
Instruments |
|
Years active | 2010–present |
Labels | Made Men |
Associated acts | |
Website | iamtonye.com |
Àárò ayé àti èkó rè
àtúnṣeTonye je omo abinibi ilu Benin ni Ipinle Edo, orílè-èdè Nàìjirià. Ìyá rè jé omobibi ìpínlè Anambra Ìyá agba rè ló fun lorukọ "Tamunotonye". Ó lo ilé-ìwé Vivian Fowler Memorial School àti Queens College ni Èkó níbi tí o ti pari èkó Sekondiri rè. [4] Ó tèsíwájú èkó rè ní yunifásitì ti Marymount
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Tonye Garrick: the singer getting Nigeria dancing". TRUE Africa. 2015-10-08. Retrieved 2022-04-06.
- ↑ "Tonye Garrick biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 2012-12-05. Retrieved 2022-04-06.
- ↑ "Tonye Garrick". DBpedia. 1983-08-27. Retrieved 2022-04-10.
- ↑ http://www.naijadeevas.com/2012/12/deeva-of-week-tonye-garrick.html. Retrieved 2022-04-06. Missing or empty
|title=
(help)