Tosin Adeloye
Tosin Adeloye (tí wọ́n bí ní 7 February 1996) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ eléré-ìárayá tó ń sáré.[1] Ó kópa nínú ìdíje irinwó mítà ní ayẹyẹ 2015 World Championships in Athletics, ní Beijing, China.[2]
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kejì 1996 | |||||||||||||
Sport | ||||||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Nigeria | |||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Track and field | |||||||||||||
Event(s) | 400 metres | |||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Ìlo oògùn olóró
àtúnṣeWọ́n ṣe àyẹ̀wò fún Adeloye ní National Sports Festival, Eko, ní oṣù kejìlá ọdún 2012, nígbà tí ó wà ní ọmọdún mẹ́rìndínlógún (16). Èsì àyẹ̀wò náà fi hàn pé ó ní anabolic steroid Metenolone lágọ̀ọ́ ara rẹ̀, èyí sì mu kí ó pàdánù àǹfààní láti máa kópa nínú eré-ìdárayá fún ọdún méjì. Ní ọjọ́ kẹfà oṣù kìíní ọdún 2015, wọ́n fun ní ààyè náà padà. [3][4]
Ó tún pàdánù àǹfààní láti máa tẹ̀síwájú nínú ṣíṣe eré-ìdárayá nígbà tí wọ́n tún ṣe àyẹ̀wò mìíràn fun ní ọdún 2016, tí wọ́n sì bá oògùn olóró ní ara rẹ̀.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Tosin Adeloye". IAAF. 24 August 2015. Retrieved 23 August 2015.
- ↑ Heats results
- ↑ "IAAF News Issue 149, 28 January 2014" (PDF). iaaf.org. IAAF. Retrieved 6 March 2015.
- ↑ "Athletes currently suspended from all competitions in athletics following an Anti-Doping Rule Violation as at: 21.05.14" (PDF). IAAF. Archived from the original (PDF) on 27 May 2014. Retrieved 9 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Akpodonor, Gowon (2 June 2016). Nigerian athlete, Adeloye, fails drug test, bags eight-year ban Archived 2024-04-08 at the Wayback Machine.. Guardian Nigeria. Retrieved on 7 August 2016.