Toyota
Toyota Motor Corporation (Japanese: トヨタ自動車株式会社 ) Toyota Jidōsha Kabushiki-gaisha (TYO: 7203 ), tabi Toyota lasan, je ile-ise lorile-ede pupo ti ibujoko re wa ni Japan ati ile-ise asemoto titobijulo laye gege bi oja tita. Awon osise ni ile-ise Toyota to bi 320,808 eniyan kakiriaye.
Type | Public (TYO: 7203 ) & (Àdàkọ:Nyse) |
---|---|
Founded | 1937 |
Founder(s) | Kiichiro Toyoda |
Headquarters | Toyota City, Aichi, Japan; Tokyo, Japan |
Key people | Kiichiro Toyoda (Founder), Fujio Cho (Chairman and Representative Director), Katsuaki Watanabe (Vice chairman and Representative Director), Akio Toyoda (President and Representative Director), Shoichiro Toyoda (Honorary Chairman)[1] |
Industry | Automotive Biotechnology |
Products | Economy/mainstream/luxury vehicles |
Revenue | ▼ USD $263.42 billion (2009)[2] |
Operating income | ▼ USD $-4.56 billion (2009)[2] |
Net income | ▼ USD $-4.33 billion (2009)[2] |
Total assets | ▼ USD $324.98 billion (2009)[2] |
Total equity | ▼ USD $-5.54 billion (2009)[2] |
Employees | 316,121[3] |
Subsidiaries | 522 |
Website | www.toyota.co.jp/en/ |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |