Ìjìláyípo Ilẹ̀-Olóoru
(Àtúnjúwe láti Tropical storm)
Ìjìláyípo Ilẹ̀-Olóoru tabi Ìjì Ilẹ̀-Olóoru (tropical cyclone tabi tropical storm) je iru iji ti arin re ni itemo rirele gbangba center ati opolopo awon iji ara ti won mu afefe lile ati ojo kikan wa. Awon ijilayipo ile-olooru n wa nitori igbona to n sele nigbati afefe rírin ba gberasoke, lati fa isupo omi oru to wa ninu afefe ririn.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |