Truong Tan Sang
Truong Tan Sang (ojoibi January 21, 1949 ni adugbo Duc Hoa, igberiko Long An, French Indochina) ni Aare ile Vietnam. Ile igbimo asofin Vietnam diboyan pelu ibo 477 (97.12%) ni July, 2011.
Trương Tấn Sang | |
---|---|
President of Vietnam | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 25 July 2011 | |
Alákóso Àgbà | Nguyen Tan Dung |
Vice President | Nguyen Thi Doan |
Olórí | Nguyen Phu Trong |
Asíwájú | Nguyen Minh Triet |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kínní 1949 Đức Hòa, French Indochina (now Vietnam) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Communist Party |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |