Tunbosun Aiyedehin

  Tunbosun Aiyedehin (tí a bí ní ọjọ́ ogún, oṣù kẹfà ọdún 1969) tí ó gbajúmò gẹ́gẹ́ bí Tuby jẹ́ òṣèré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa Two Brides and a Baby àti Kpians: The Feast of Soul

Ìgbésí ayé rẹ̀Àtúnṣe

Iṣẹ́Àtúnṣe

Ó kópa nínú eré bíi Hakkunde, Troubled Waters, Moth to a Flame, Hell or High Water, Lockdown, Dear Bayo, Mrs. & Mrs. Johnson and The Ten Virgins lẹ́yìn ìgbà tí ó darapọ̀ mọ́ Nollywood. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin tí ó dára jù lọ nínú eré dírámà láti ọ̀dọ̀ African Magic ní ọdún 2016. Ó gba àmì ẹ̀yẹ Best of Nollywood Awards ni ọdún 2019 gẹ́gẹ́ bí òṣèré bìnrin tí ó dára jù lọ.

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀Àtúnṣe

 • Two Brides and a Baby (2011)
 • Kpians: The Feast of Souls (2014)
 • A Day with Death (2014)
 • Mrs. & Mrs. Johnson (2015)
 • Before 30 (2015)
 • Schemers (2015)
 • Moth to a Flame (2016)
 • 93 Days (2016)
 • Hell or High Water (2016)
 • Oreva (2017)
 • Hakkunde (2017)
 • Troubled Waters (2017)
 • E.V.E - Audi Alteram Partem (2018)
 • The Ten Virgins (2019)
 • Black Monday (2019)
 • Clustered Colours (2019)
 • Lockdown (2019)
 • Stones (2019)
 • The Sessions (2019)
 • Dear Bayo (2020)
 • It's a Crazy World (2020)
 • Mirabel (2020)
 • Yahoo Taboo (2020)
 • Country Head (2020)

Àmì ẹ̀yẹÀtúnṣe