Tunde Baiyewu (abiso Tunde Emanuel Baiyewu, ni 25 November 1965, London) je akorin olohungbangba omo Nigeria ara Britani ti ofigba kan je ikan ninu egbe olorin Lighthouse Family. Ni 2004 o bere ise orin solo, o si gbe awo orin kan jade to n je, Tunde.

Tunde Baiyewu
Background information
Orúkọ àbísọTunde Emanuel Baiyewu
Ìbẹ̀rẹ̀London
Irú orinPop, Easy listening
Occupation(s)Singer
Years active1993–present
LabelsPolydor (1993–2003)
RCA Records (2004–present)
Associated actsLighthouse Family