Tunde Eso

Oníwé-Ìròyín

Tunde Eso (tí a bí ní ọjọ́ 16 oṣù August, ọdún 1977) jẹ́ akọ̀ròyìn ọmọ orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà, alásọyé nípa ọ̀rọ̀ àwùjọ, àti olóòtú ìwé-ìròyìn Findout.[1] Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ PDP tó díje dupò gómìnà ipinle Osun ní ọdún 2018.[2][3][4] Eso ni olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ Youthocracy; Ààrẹ Fix Nigeria Group àti òǹkọ̀wé àwọn ìwé African Security Solution and Vision for Africa.[5]

Tunde Eso
Ọjọ́ìbíTunde Eso
16 Oṣù Kẹjọ 1977 (1977-08-16) (ọmọ ọdún 47)
Ilesa, Osun State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Blogger, businessman, lecturer; journalist
Websitetundeeso.com

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe