Tunde Olukotun

ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Electrical Engineering àti Computer Science ní Stanford University, àti olùdarí láàbù Stanford Pervasive Parallelism

Oyekunle Ayinde "Kunle" Olukotun jẹ́ ọmọ Britain tó tún tan mọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà[1] jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ, tó sì tún jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti Cadence Design Systems Professor ní Stanford School of Engineering, ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ìmọ̀ Electrical Engineering àti Computer Science ní Stanford University, àti olùdarí láàbù Stanford Pervasive Parallelism.[2] [3][4]

Tunde Olukotun
ÌbíOyekunle Ayinde Olukotun
London, England
Pápáhigh-performance computer architecture; parallel computing
Ilé-ẹ̀kọ́Stanford University
Doctoral advisorTrevor Mudge
Ó gbajúmọ̀ fún
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Nigeria Techstars Series - Prof Kunle Olukotun of Stanford University". 22 April 2011. 
  2. "Kunle Olukotun's Profile | Stanford Profiles". profiles.stanford.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-09-20. 
  3. "SambaNova Systems Announces $150M Series B From Intel Capital and GV to Advance Its Breakthrough AI Platform". AP NEWS. 2019-04-01. Retrieved 2020-09-20. 
  4. "Stanford profs' AI hardware startup scores $250M at unicorn valuation". www.bizjournals.com. Retrieved 2020-09-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)