Tuwon shinkafa
Tuwon Shinkafa jẹ́ òkèlè ìrẹsì Nàìjíríà àti ẹ̀yà Nàìjíríà láti Niger àti Àríwá Nàìjíríà.[1][2][3] Ó jẹ́ oúnjẹ tí wọ́n máa ń ṣe láti ara ìrẹsì tiwantiwa tí ó ti rọ̀ tí ó sì yi, tí wọ́n sì sábàá máa ń jẹ pẹ̀lú orísìírísìí ọbẹ̀ bí Miyar Kuka, Miyar Kubewa, àti Miyar Taushe.[4][5] Orísìí méjì ni wọ́n máa ń ṣe láti ara àgbàdo àti ọkà bàbà ni à ń pè ní Tuwon Masara and Tuwon Dawa, tẹ̀léńtèlé.[6][7][8] Ní Ghana, Omo Tuo ni wọ́n ń pe Tuwon Shinkafa.
Tuwon shinkafa | |
Type | Tuwo, swallow |
---|---|
Place of origin | Nigeria |
Region or state | Northern Nigeria |
Associated national cuisine | Nigerian cuisine |
Serving temperature | Hot, usually rolled up in spherical form |
Main ingredients | Rice, maize or millet |
Àdàkọ:Wikibooks-inline
|
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "How to make Tuwon Shinkafa (Rice Fufu)". All Nigerian Recipes. Retrieved 6 July 2015.
- ↑ "Cuisine of Nigeria: Tuwo shinkafa". Trek Zone (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-04.
- ↑ "Three Delicious Delicacies, North of the Niger". Google Arts & Culture (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-04.
- ↑ Brown, Ed (2020-03-30). "How to Prepare Tuwo Shinkafa and Miyan Taushe". Royac Shop (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-04.
- ↑ "Simple Way to Make Ultimate Tuwon shinkafa d miyar kuka | Quick and Easy Recipes". familycooking.pages.dev. Retrieved 2022-05-04.
- ↑ "Tuwo Shinkafa (Tuwon Shinkafa) - made from Raw rice and also with Rice flour". Nigerian FoodTV. 23 August 2014. Retrieved 6 July 2015.
- ↑ Eshemokha, Udomoh (2020-07-31). "TUWO MASARA: Health Benefits, How to prepare Tuwo Masara, Tuwo Masara Recipes" (in en-US). https://nimedhealth.com.ng/2020/07/31/tuwo-masara-health-benefits-how-to-prepare-tuwo-masara-tuwo-masara-recipes/.
- ↑ "How to Make Tuwon Dawa: Nigerian Guinea Corn Fufu". 9jafoods (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-30. Retrieved 2022-05-04.