Twitter jé ìkànnì ibanidore lórí èro ayelujara, o gbà àwon olùmúlò rè láti fi òrò ránsé si arawon àti láti fí òrò ranse sí afefe. A lè lo ìkànnì ibadore Twitter lórí èro alagbeka, komputa tábìlì àti komputa alagbeka. A da kalè ní odun 2006 [1]

Awon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Twitter launches". HISTORY. 2019-06-28. Retrieved 2022-03-05.