US Army School of Infantry

United States Army Infantry School tí ó wà ní ìlú Fort Benning ni Ìpínlẹ̀ Georgia jẹ́ ilé-ìwé tí ó wà fún kíkọ́ àwọn ológun ilẹ̀ Amerika, United States armed forces.

Àmì Ilé ìwé United States Army Infantry

Ètò ilé-ìwé

àtúnṣe

llé-ìwé náà pín sí ẹ̀ka oríṣiríṣi, bíi:

  •   Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndílọ́gbọ̀n
    • Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹrìndíláàádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kẹta, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kẹta, ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnléláàádọ́ta
  •   Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejìdínláàádọ́ẁá
    • Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlógún
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun eleekokandinlogun
    • Ọ̀wọ́ kìíní, Àwọn ọmọ-ogun àádọ́ta
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnléláàádóta
    • Ọ̀wọ́ kejì, Àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlọ́gọ́ta

Fún àwọn èèyàn to ṣẹ̀ṣẹ̀ wọlé, ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kẹtàdínláàádọ́wàá àti ẹlẹ́ẹ̀kejìdínláàádọ́ẁá máa ń gba ẹ̀kọ́ fún ọ̀sẹ̀ méjìlélógún[1]. Àfojúsùn àwọn ọ̀wọ́ yìí ni láti ṣe ìyípadà fún àwọn ará-ìlú láti di ọmọ-ológun tó já fáfá, tó kúnjú òṣùwọ̀n, tó ní ìwà ọmọ-ológun, tó dúró ire, tó níwà gidi, tó sì ń ṣiṣẹ́ dédé kí wón ba lè nì ìtẹ́wọ́gbà sínú ẹgbẹ́ náà.

  •   Àwọn ọmọ-ológun ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínláàádọ́ẁá[2]
    • Ọ̀wọ́ kejì, ọmọ-ogun ìkọkànlá
    • Ọ̀wọ́ kẹta, ọmọ-ogun ìkọkànlá
    • Ọ̀wọ́ kẹta, ọmọ-ogun ìkọkànlélọ́gọ́rin
    • Ìwé àwọn akọgun
    • Akádẹmì àwọn ológun aláìnígbìmọ̀ ti Henry Caro[3]
      • Ẹ̀kọ́ àwọn adarí àgbà ti Maneuver tí ó fìgbà kan jẹ́ ẹ̀kọ́ àwọn ológun aláìnígbìmọ̀[4]
      • Àfikún ẹ̀kọ́ àwọn àgbà adarí tí ó fìgbà kan jẹ́ ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún àwọn ológun aláìnígbìmọ̀[5]
      • Ẹ̀kọ́ àwọn adarí ogun tí ó fìgbà kan jẹ́ ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún ìdàgbàsókè àwọn adarí[6]
  •   Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn ológun ti òfurufú[7]
    •   Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun eleekerin
      • Ile-iwe awon ọmọ-ogun (ti Benning)
    •   Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀karùn-ún
      • Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun (ti Mountain)
    •   Ìdánilẹ́kọ̀ọ́awon ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹfà
      • Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun (ti inú-irà)
    •   Ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ogun kìíní, Ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun ẹlẹ́ẹ̀kejelélẹgbẹ̀fà
      • Ilé-ìwé àwọn ajagun ti orí òfurufú
      • Ilé-ìwé àwọn jumpmaster
      • Àwon ọmọ Silver-wings
  • Adarí ajagun àpapọ̀

Àwọn ọmọ-ogun tó ti parí ẹ̀kọ́ ìpìlẹ̀ fún àwọn adarí máa ń lọ sí ọ̀wọ́ kejì láti gba Ìdánilẹ́kọ̀ọ́. Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí wà fún ìgbaniníyànjú àti ẹ̀kó tó yè koro, kí wọ́n ba lè nímọ̀ nípa ìbọn lílò àti ìmọ̀ọ́ṣe nìgbogbo ọ̀nà.

Ọ̀wọ́ àwọn ọmọ-ogun yìí tún máa gbé Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kalẹ̀ fún ìmọ̀ níní nínu ogun orí òfurufú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Adarí ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun

àtúnṣe

Adarì ilé-ìwé àwọn ọmọ-ogun máa ń jẹ́ olórí àti olùdarí ilé-ìwé yìí.[8]

No. Àwòrán Orúkọ Ìbẹ̀rẹ̀ Òpin
1 Colonel Henry E. Eames 5 October 1918 22 April 1919
2 Major General Charles S. Farnsworth[9] 22 April 1919 31 July 1920
3   Brigadier General Walter H. Gordon 1 August 1920 8 November 1923
4   Brigadier General Briant H. Wells 9 November 1923 8 March 1926
5 Brigadier General Edgar T. Collins 9 March 1926 1 May 1929
6   Brigadier General Campbell King 2 May 1929 31 May 1933
7 Brigadier General George H. Estes 1 June 1933 30 September 1936
8 Brigadier General Asa L. Singleton 1 October 1936 31 August 1940
9   Major General Courtney Hodges 1 September 1940 3 March 1941
10   Major General Omar N. Bradley 4 March 1941 10 February 1942
11 Major General Leven C. Allen 11 February 1942 18 September 1943
12   Major General Charles H. Bonesteel Jr. 19 September 1943 27 June 1944
13   Major General Fred L. Walker 28 June 1944 11 July 1945
14   Major General John W. O'Daniel 12 July 1945 1 July 1948
  Major General John W. Foss[10] 1983 1985
  Major General Kenneth C. Leuer[11] 1987 1989
47   Major General Benjamin Freakley[12] 2003 2005
48   Major General Walter Wojdakowski[13] 2005 2008
49   Major General Michael Barbero[13] 2008 2009[14]
50   Major General MIchael Ferriter[15] 2009 2009
51   Brigadier General Bryan Owens[16] 2009 2011
52   Brigadier General Walter E. Piatt[17][18] 2011 2012
53   Brigadier General David B. Haight[19] 2012 2013
54   Colonel Robert E. Choppa[20] 2013 2014
55   Brigadier General James E. Rainey[21] 2014 2015
56   Brigadier General Peter Jones[22] 2015 2017
57   Brigadier General Christopher T. Donahue[23] 2017 2018
58   Colonel Townley R. Hedrick[24] 2018 2018
59   Major General David M. Hodne [24] 2018 2021
60   Brigadier General, Larry Q. Burris Jr.[25] 2021 Current

Àwọn ìtọkasí

àtúnṣe
  1. 22-Week One Station Unit Training Archived 10 November 2011 at the Wayback Machine.
  2. Staff (n.d.). "199th Infantry Brigade". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 2 February 2021. Retrieved 16 January 2021. 
  3. Staff (n.d.). "Henry Caro Noncommissioned Officer Academy". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 19 March 2016. Retrieved 21 March 2016. 
  4. Staff (n.d.). "Maneuver Senior Leaders Course". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 18 January 2021. Retrieved 16 January 2021. 
  5. Staff (n.d.). "Infantry Advanced Leaders Course". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 12 November 2020. Retrieved 16 January 2021. 
  6. Warrior Leaders Course[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  7. Staff (n.d.). "Airborne and Ranger Training Brigade". www.benning.army.mil. United States Army. Archived from the original on 11 March 2022. Retrieved 21 March 2016. 
  8. "Office of the Chief of Infantry". United States Army Maneuver Center of Excellence. United States Army. 2 August 2012. Archived from the original on 31 January 2013. Retrieved 2 February 2013. 
  9. Emerson, William K. (2004). Marksmanship in the U.S. Army: A History of Medals, Shooting Programs, and Training. University of Oklahoma Press. p. 101. ISBN 9780806135755. https://books.google.com/books?id=OdHtJ9-jCsIC&q=1st+%22Chief+of+Infantry%22+Farnsworth&pg=PA101. Retrieved 2 February 2013. 
  10. "Army's chief of infantry will take over Ford Bragg". Star-News. Associated Press. 26 December 2009. https://news.google.com/newspapers?id=KklOAAAAIBAJ&pg=3875%2C8158823. 
  11. "Fort Benning has always been Kenneth Leuer's home away from home". Columbus Ledger-Enquirer. Columbus Ledger-Enquirer. 28 October 2018. https://www.ledger-enquirer.com/news/local/article220685600.html. 
  12. "Lieutenant General Benjamin C. Freakley" (PDF). ArmyEdSpace.com. United States Army. Retrieved 10 February 2013. 
  13. 13.0 13.1 Bennett, Doraine (2008). "A Retrospective: MG Walter Wojdakowski, Chief of Infantry, August 2005 – November 2008". Infantry Bugler (National Infantry Association): 8–9. ISSN 1933-6225. Archived from the original on 27 August 2011. https://web.archive.org/web/20110827103532/https://www.infantryassn.com/Bugler%20issues/Winter_2008.pdf. Retrieved 10 February 2013. 
  14. Little, Vince (5 June 2009). "CG reflects on tenure at Fort Benning". The Bayonet. United States Army. Retrieved 10 February 2013. 
  15. Sitter, Bridgett (22 September 2009). "Leaders discuss future of Infantry, Armor". MCOE Public Affairs. United States Army. Retrieved 10 February 2013. 
  16. Little, Vince (8 June 2011). "Chief of Infantry bids farewell to Benning". The Bayonet. United States Army. Retrieved 2 February 2013. 
  17. Àdàkọ:Cite AV mediaÀdàkọ:Cbignore
  18. Little, Vince (3 August 2011). "Post hails new chief of Infantry". News Archive. United States Army. Retrieved 2 February 2013. 
  19. Ben Wright (2 August 2012). "Fort Benning announces new commanders for Infantry and Armor Schools". Columbus Ledger-Enquirer. Archived from the original on 21 September 2013. https://web.archive.org/web/20130921055732/http://www.ledger-enquirer.com/2012/08/02/2144190/fort-benning-announces-new-commanders.html. 
  20. "New Infantry chief takes command". The Bayonet. 4 December 2013. Archived from the original on 4 March 2016. https://web.archive.org/web/20160304002220/http://www.thebayonet.com/2013/12/04/513581/new-infantry-chief-takes-command.html. 
  21. "Fort Benning welcomes new infantry chief and commandant". Columbus Ledger-Enquirer. 30 July 2014. Archived from the original on 17 October 2014. https://archive.is/20141017023259/http://www.ledger-enquirer.com/2014/07/30/3224831_fort-benning-welcomes-new-infantry.html. 
  22. "Fort Benning to welcome new infantry chief Brig. Gen. Peter Jones". Columbus Ledger-Enquirer. 24 September 2015. http://www.ledger-enquirer.com/news/local/military/article36455706.html. 
  23. "Brig. Gen. Donahue is 57th chief of infantry at Fort Benning". Columbus Ledger-Enquirer. 15 August 2017. http://www.ledger-enquirer.com/news/local/military/article167426392.html. 
  24. 24.0 24.1 Gatchell, Bryan (3 August 2018). "New Commandant Takes Responsibility of US Army Infantry School". U.S. Army. https://www.army.mil/article/209432/new_commandant_takes_responsibility_of_us_army_infantry_school. 
  25. "Soldier Lethality CFT welcomes new director". 2021-08-12. 

Ìjápọ̀ mìíràn

àtúnṣe