Uche Ogbodo (tí a bí ní Oṣù Kaàrún Ọjọ́ 17, Ọdún 1986) jẹ́ òṣèré fíìmù àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Uche Ogbodo
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kẹrin 1986 (1986-04-17) (ọmọ ọdún 38)
Ipinlẹ Enugu, Naijiria
Iṣẹ́Oṣere

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àtúnṣe

A bí Ogbodo ní Ìpínlẹ̀ Enúgu. Ìrìn-àjò Ogbodo sí Nollywood bẹ̀rẹ̀ lẹ́hìn ìpinnu bàbá rẹ̀ láti forúkọ rẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ Actors Guild of Nigeria ní Ìpínlẹ̀ Enúgu.[2] Láti ìgbà eré àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 2006, ó ti ṣe bẹ́ẹ̀ kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù lẹ́hìn náà.[3]

Àṣàyàn eré rẹ̀ àtúnṣe

  • Be My Val
  • Family Romance
  • Festac Town
  • Forces of Nature
  • Four Sisters
  • Gamblers
  • Girl Child (2018)
  • Broken Pieces (2018)
  • His Holiness
  • His Last Action
  • Honour My Will
  • The Laptop
  • Light Out
  • Over Heat
  • Ovy's Voice
  • Power of Beauty
  • Price of Fame
  • Raging Passion
  • Royal Palace
  • Sacrifice for Marriage
  • Simple Baby
  • Spirit of Twins
  • Turning Point
  • Yankee Girls
  • Mummy Why (2016)
  • Commitment Shy
  • Only Love
  • Caught-up

Àwọn àmì ẹ̀yẹ àtúnṣe

Ọdún Ayẹyẹ Ẹ̀bùn Èsì itọkasi
2015 2015 Fashion Icon Awards Fashion Icon Gbàá [4]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe